English - Yorùbá Dictionary

Con

Constabulary noun. /  ẹgbẹ́ ọlọ́pàá.

Constant adj. /  dídúró ṣinṣin, tí kò yípadà.

Constantly adv. /  léraléra, fírífírí, nígbàgbogbo.

Constitution noun. /  òfin, ẹ̀dá ara.

Constrain verb. /  fi agbára ṣe, rọ̀.

Construct verb. /  kọ́, ṣ e, kàn.

Construction noun. /  kíkọ́, síse, kíkàn, ìtumọ̀ ọ̀rọ̀.

Consul noun. /  aṣojú ìjọba kan ní ilẹ̀ míràn.

Consulate noun. /  oyè aṣojú ìjọba kan ní ilẹ̀ míràn.

Consult verb. /  béèrè, fi ọràn lọ̀, wáàdí ọ̀rọ̀, rò, jíròrò.

Consultant noun. /  agbani nímọ̀ràn, apèrò, alámọ̀ràn.

Consultation noun. /  ìbéèrè, ìfọrànlo, ìbádámọ̀ràn.

Consume verb. /  run, fi ṣòfò, jẹ tan, fi jóná, jẹ.

Contact noun. /  ìfarakanra. verb. / ìpàdé.

Contagious adj. /  ríràn.

Contain verb. /  fi-pẹ̀lú, gbà-sínú, ní nínú.

Contaminate verb. /  bà jẹ́.

Contamination noun. /  ìbàjẹ́.

Con

Contemplate verb. /  ṣe-àsàrò, ronú, wò.

Contemplation noun. /  ìrò, àṣàrò, wíwò.

Contempt noun. /  ẹ̀gàn, ìkẹ́gàn, àìkàsí, wíwò, ìfojú tínrín.

Contemptible adj. /  lẹ́gàn, láìnílárí, sàìní lárí.

Contemptuously adv. /  tìkà tẹ̀gbin.

Contend verb. /  jìjàdù, ja, ba díje, ba jiyàn.

Content adj. /  nítẹ̀lọ́rùn.

Contest verb. /  jà, jiyàn, ja ìjàdù.

Continence noun. /  ìmáradúró, àkóso ìwà.

Continent noun. /  ẹ̀yà àgbáyé.

Continually adv. /  títí, títílọ, léraléra.

Continuation noun. /  ìfàpẹtítí, àìdúró, ìbálọ, ìtẹ̀síwájú.

Continue verb. /  tẹ̀-síwájú, dúró pẹ́, jingíri, wà títí.

Continuous adj. /  àbálé-àbálé.

Contort verb. /  lọ́pọ̀, tẹ̀, kákò.

Contraband noun. /  ohun ìlòdì sí òfin, ohun tí òfin kọ.

Contraceptive noun. /  ogun ìdíwọ́ oyún.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba