English - Yorùbá Dictionary

Con

Contract noun. /  ìpínhùn, àdéhùn, ìpinnu. verb. / dínkù.

Contraction noun. /  ìkékúrú.

Contradict verb. /  jì-lẹ́sẹ̀, jà-níyàn, takò, gbó-lẹ́nu.

Contradiction noun. /  ijìlẹ́sẹ̀, ijàníyàn, itakò, igbólẹ́nu.

Contrariwise adv. /  ni ilòdìsí.

Contrary adj. /  lòdì.

Contrast noun. /  ìfiwéra, ìfíyàtọ̀ sí, ìyàtọ̀.

Contribute verb. /  dá, fi-fún, rànlọ́wọ́, dá owó.

Contribution noun. /  ìdáwó, ìrànlọ́wọ́.

Control noun. /  agbára, ìjánu. verb. / kó níjàánu, ṣàkóso.

Controversy noun. /  àròyé, àríyànjiyàn, gbólóhùn asọ̀.

Conundrum noun. /  àlọ́.

Convalescence noun. /  ìwòsàn, lílágbára lẹ́hìn ìwòsàn.

Convene verb. /  pe àpèjọ.

Convenience noun. /  ìrọ̀rùn, ànfàní.

Convenient adj. /  yẹ, rọrùn, ṣe-dédé, ṣànfàní, pèsè.

Convention noun. /  àpéjọ.

Conversation noun. /  ọ̀rọ̀ sísọ.

Con

Conversion noun. /  ìyípadà, ìyílọ́kànpadà.

Convert verb. /  yí-padà, yílọ́kàn-padà.

Convey verb. /  mú-lọ, rù, fi-fún, rán.

Convict noun. /  ẹnití a dálẹ́bi, ẹnití a dálẹjọ.

Conviction noun. /  ìdálẹ́bi, ìdálẹ́jó.

Convince verb. /  dá-ni lójú, yí lọ́kàn padà, fi òye yé.

Convincing adj. /  ohun ìdánilójú, dídánilójú.

Convocation noun. /  ipejọpọ̀, apejọ.

Convoke verb. /  pé, apejọ.

Convulsion noun. /  ipá, gìrì, àìperí.

Cony noun. /  ehoro.

Cook noun. /  alásè, ase-onjẹ. verb. / sè, se ohun jíjẹ.

Cool adj. /  tútù, fẹ́ri. verb. / mú tútù, mú fẹ́ri.

Coop adj. /  ilé adiẹ, àgo.

Co-operate verb. /  bá-sísẹ́, po,jùmọṣe.

Co-operation noun. /  ìfowósowópọ, ìbásepọ, àjùmose.

Copy noun. / ẹdà àwòkọ, ìwé-kíkọ, àtúnkọ, àpẹ́rẹ, àwòrán.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba