English - Yorùbá Dictionary

Cer

Certain adj. /  dájú.

Certainly adv. /  dájú-dájú, láìsí àníàní, nítòótọ, dandan.

Certainty noun. /  ìdánilójú, àìsiyèméjì.

Certificate noun. /  ìwé èrí.

Certify verb. /  jẹri, íròyìn, mú dájú.

Chain noun. /  ẹ̀wọn.

Chair noun. /  àga ìjokó.

Chairman noun. /  aláàga, olórí àjọ, olórí àpèjọ.

Chalk noun. /  ẹfun.

Chamber noun. /  iyàrá, ìyẹ̀wù.

Chameleon noun. /  ọgà.

Chamois noun. /  ewúrẹ́ igbó.

Champion noun. /  ọ̀gágun, oníṣẹ́gun, aṣaju nkan.

Chance noun. /  àyè, alábàápàdé, èsì.

Chancellor noun. /  asíwájú olórí ilé-eko gíga, amòfin.

Change noun. /  ìyípadà, ìparadà, pàrọ.

Changeable adj. /  ti nyípadà .

Channel noun. /  ìsàlẹ̀ odò, orísi ọ̀nà láti wo telefísọ̀n.

Cha

Channel noun. /  ọ̀nà ti angbà ṣe nkan.

Chant verb. /  kọrin.

Chaos noun. /  ìdàrúdàpọ̀.

Chaotic adj. /  ní rúdurùdu.

Chap noun. /  ọmọdékọ̀nrin.

Chapel verb. /  ilé Ọlọ́run kékeré.

Chaplain noun. /  oníwàásù ní ilé Ọlọ́run tàbí ọmọ-ogun.

Chapter noun. /  orí ìwé, ìpín ìwé.

Character noun. /  ìwà, orúkọ, ami ohunkohun.

Charcoal noun. /  èédú igi.

Charge noun. /  ìdíyelé, ìnákúnàá, ẹ̀sùn, fisùn.

Charge verb. /  fún-lágbára, ìpasẹ fún, ifisùn.

Charity noun. /  ìfẹ́ni, ọrẹ-àánú .

Charm noun. /  òògùn, ondè, tírà, ògèdè.

Chart noun. /  ìwé àwòrán àpẹrẹ.

Charter verb. /  háyà.

Chase verb. /  lépa, dọdẹ. noun. / ìwé adehùn

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba