English - Yorùbá Dictionary

Cat

Casualty noun. /  ífarapa, kọ lójú ìjà.

Cat noun. /  ológìnní, ológbò.

Catalogue noun. /  ìwé orúkọ, ìwé ìpolówó ọjà.

Catastrophe noun. /  ìparí àìdára, àjálù, ìjàmbá.

Catch verb. /  mú, dá dúro, ramu, hán, gán.

Category noun. /  ẹ̀yà.

Cater verb. /  pèsè onjẹ.

Caterer noun. /  onípèsè onjẹ.

Caterpillar noun. /  kòkòrò.

Cathedral noun. /  ilé ìjọ́sìn nlá.

Cattle noun. /  ẹran ọ̀sìn.

Cause noun. /  ìdí, ìtorí. verb. / dá sílẹ̀, bá wá.

Caution noun. /  ìwòye, ọgbọ́n, àkíyèsí, ìkìlọ̀, ìṣílétí.

Cautious adj. /  nísọra, níwòye.

Cavalry noun. /  ogun ẹlẹ́ṣin.

Cave noun. /  ihò nínú àpáta, ihò inú ilẹ̀.

Cavern noun. /  ihò nísàlẹ̀ ilẹ̀.

Cavil noun. /  àwáwí èké.

Cav

Cavity noun. /  ihò inú eyín.

Cayenne noun. /  ata pupa.

Cease verb. /  dáwọ́dúró, wawọ́, síwọ́,dá, dẹ́kun.

Cedar noun. /  igi òpepe.

Ceiling noun. /  òkè àjà, àjà ilé.

Celebrate verb. /  sè rántí, sọdún nkan.

Celebration noun. /  ayẹyẹ, ìnáwó ìyìn ìrántí.

Cell noun. /  ẹ̀yà-ara, yàrá ẹlẹ́wọ̀n.

Cellar noun. /  yàrá ísàle ilé.

Cement noun. /  amọ̀ líle.

Cemetery noun. /  ìtẹ́ òkú, ibi ìsìnkú.

Censure noun. /  ìbáwí.

Census noun. /  kíkà ènìyàn ní ìlú.

Center noun. /  àárín, agbedeméjì.

Century noun. /  ọgọ́run ọdún.

Ceramic adj. /  ohun èlò amọ̀.

Ceremonial adj. /  síse àpejọ tàbí ìsìn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba