English - Yorùbá Dictionary

Des

Design noun. /  ìrò, ìmò, àpẹrẹ, àwòrán.

Designate verb. /  pè lórúkọ, sàmì sí, yàn.

Desirable adj. /  yẹ ni fífẹ́.

Desire noun. /  ìfẹ́ ìwù.verb. / fè, beere.

Desist verb. /  ṣíwọ́, dá ọwọ́ dúró.

Desk noun. /  àpótí ìwé, ibití á ti nkọwé.

Desolate verb. /  sọ di ahoro.

Desolation noun. /  isọdahoro.

Despair noun. /  àìnírètí.

Despatch verb. /  rán lọ kíakía. noun / ìranlọ, ìyara.

Desperate adj. /  láìnírètí, láìdábà, fi àáké kọ rí.

Despise verb. /  kẹ́gàn, fi ṣẹ̀sín, pẹ̀gàn.

Despite prep. /  bí ó tilẹ̀ jẹ pé.

Despoil verb. /  kó lẹrù, ja lólè.

Dessert noun. /  èso àjẹkẹ́hìn oúnje.

Destination noun. /  òpin ìrìnàjò, òpin nkan.

Destine verb. /  kádàrá, yàn fun, pinnu.

Destiny noun. /  òpin nkan, òpin ẹnìkan, àyànmọ́-ìpín.

Des

Destitute adj. /  láìní, kíkọsílẹ̀, ní tálákà, àbòṣí, òṣì.

Destroy verb. /  parun, rún, parẹ́.

Destroyer noun. /  apani, arunni.

Destruction noun. /  ìparun, ìparẹ́, ìsọdasán.

Detach verb. /  yà, yà sọ́tọ̀, wọ́n-nù.

Detached adj. /  tí a lè yà sọ́tọ̀, ọ̀tọ̀tọ̀.

Detachment noun. /  ẹ̀gbẹ́ àyasọ́tọ̀.

Detail noun. /  rírò lọkọkan.

Detain verb. /  dá-dúró, tì-mọ́lé.

Detect verb. /  wá-rí, jádi.

Detection noun. /  ìwá-rí, ihù sílẹ̀-ìfihàn.

Detective noun. /  ọlọ́pàá inú, ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́.

Detention noun. /  ìdánidúró.

Deter verb. /  dá dúró.

Determination noun. /  ìpinnu.

Determine verb. /  pinnu, fọwọ́-sọ̀yà, ròpin.

Detest verb. /  kórira si nkan.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba