HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Dem
Demonstration
noun.
/ ìfihàn, ìṣehanni.
Demur
verb.
/ ṣiyèméjì, ṣe àníàní, kọ̀.
Den
noun.
/ ẹranko ihò.
Denial
noun.
/ sísẹ́, kíkọ̀.
Denote
verb.
/ sami si, toka si.
Denounce
verb.
/ báwí, jẹ́rí sí, kìlọ.
Dense
adj.
/ ki, nípọn, dídì, gọ̀.
Dent
noun.
/ ìtẹsínú.
verb.
/ tẹ̀ sínú.
Dentist
noun.
/ oníṣègùn eyín.
Denunciation
noun.
/ ìkìlọ̀ nígbangba.
Deny
verb.
/ dù, sẹ́, kọ̀ fún, gbónu.
Depart
verb.
/ lọ, kúrò, kú, kángárá.
Department
noun.
/ apá, ìsọ̀, sàkaaní.
Departure
noun.
/ ilọ, kurò, iku, àtilọ.
Depend
verb.
/ gbẹ́kẹ̀lẹ́, gbáralé, gbíyelé, gbójúlé.
Dependence
noun.
/ ìgbáralé, ìgbẹ́kẹ̀lé, ìgbójúlé.
Dependent
noun.
/ ìbátan, ẹnití ó wà lábẹ́ ìtọ́jú ẹni.
Deploy
verb.
/ rán, gbáradì fún isẹ́ miràn.
Dep
Deport
verb.
/ lé kúrò ní ìlú, hùwà, lò.
Deportation
noun.
/ lílé kúrò ní ìlú.
Depose
verb.
/ mú kúrò nípò, rọ lóyè.
Deposit
noun.
/ ohun ìdógó, àdáwin, ohun ìfisílẹ̀.
Depot
noun.
/ ile ìṣúra, ibi ìpamọ́, èbúté ọkọ̀, èbúté èrò.
Depression
noun.
/ ìrẹsílẹ, ìrẹwẹsí, ìdorí kodò.
Deprive
verb.
/ gbà lọ́wọ́ ẹni, rọ̀ lóyè, gbàloyè.
Depth
noun.
/ jíjìn, ìjìnlẹ̀ ìbú.
Depute
verb.
/ fún ní àsẹ.
Depute
noun.
/ aṣojúẹni, adelé.
Deride
verb.
/ fi ṣẹ̀sín, fi ṣe ẹlẹ́yà, fi rẹ́rin.
Descendant
noun.
/ àtẹ̀lé.
Describe
verb.
/ fọ̀rọ̀ sàpẹrẹ, so bí ó ti rí, ṣàpèjúwe.
Description
noun.
/ àpẹrẹ, ìsàpere, àpèjúwe.
Desert
noun.
/ aginjù, aṣálẹ̀.
verb.
/ kọ̀ sílẹ̀, fi-sílẹ̀.
Desertion
noun.
/ ìkọsílẹ, ìyọsílẹ̀.
Deserve
verb.
/ yẹ, tọ́-sí.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.