English - Yorùbá Dictionary

Dis

Disappear verb. /  farasin, kúrò lójú, mú mọ ni lójú, mú.

Disappearance noun. /  ìfarasin, ìmú mọ ni lójú.

Disappoint verb. /  yẹ àdéhùn.

Disapprove verb. /  kọ̀, ṣaláìfe, ṣàìgbà.

Disarm verb. /  gba agbára kúrò, gbà óhun ìjà .

Disaster noun. /  ewu nlá, ìjábà, àjálù, jàmbá.

Disastrous adj. /  ní jàmbá.

Disband verb. /  túká.

Disbelief noun. /  àìgbàgbọ.

Discard verb. /  mú kúrò, yọ kúrò, kọ̀ sílẹ̀.

Discharge noun. /  yọ kúrò ní isẹ́, sọ di òmìnira.

Discipline noun. / ìkóníjanu, ìbáwí, jẹ níyà.

Disclose verb. /  fi hàn.

Disclosure noun. /  ìfihàn.

Discomfort noun. /  ìnira, ìrora, àìní àláfíà, ìbànújẹ́.

Disconnect verb. /  yọ kúrò, pín níyà.

Discount noun. /  ìyọkúrò, ìdín owó kù, ìdínkù.

Discourage verb. /  ṣàìgbàníyànjú, mú ìrẹwẹsi bá.

Dis

Discover verb. /  wá-rí jágbọ́n.

Discovery noun. /  àwárí, ìjágbọ́n.

Discreet adj. /  gbọn nísọra, lóye, farabàlẹ̀.

Discreetly adv. /  tòyetòye.

Discrepancy noun. /  ìyàtọ̀, àìbá dọ́gba.

Discretion noun. /  ọgbọ́n inú, ọgbọ́n òye, lákàyè.

Discriminate verb. /  fiyàtọ̀, sísàmì sí, yánjú.

Discrimination noun. /  ẹlẹ́yàmẹ́yà, àmì ọ̀tọ̀, ìfì-ìyàto sí.

Discuss verb. /  sọ kíníkíní, wádi ,jíròrò.

Discussion noun. /  ìwadìí, ìjíròrò, àsọgbà ọ̀rọ̀.

Disdainful adj. /  gígàn, lẹ́gàn.

Disease noun. /  àrùn, ọ̀kùnrùn.

Disfigure verb. /  bà lára jẹ́.

Disgrace noun. /  ojútì, ẹ̀gàn, ìtìjú, ẹ̀tẹ́.

Disgraceful adj. /  ohun ìtìjú, tinilójú.

Disguise verb. /  pa-radà.

Disgust noun. /  ìrira, sísú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba