English - Yorùbá Dictionary

Dis

Dishonest adj. /  láìṣotọ́, oní makarúrù, ayédèrú ènìyàn.

Disinter verb. /  hú jáde.

Disjoin verb. /  yà sọ́tọ̀, gé kúrò, túká.

Dislike noun. /  ìrira, aifẹ́.

Dislodge verb. /  le kúrò ni ibi ìsádi.

Disloyal adj. /  tí kò forí balẹ̀ fún ọba.

Dismantle verb. /  tú-palẹ̀, tú-kalẹ̀.

Dismiss verb. /  lé-lọ, rán-lọ, yọ kúrò.

Dismissal noun. /  ìránlọ,ìyọ kúrò nísẹ́, ìtúká.

Disobedience noun. /  àìgbọ́ràn àfojúdi.

Disobedient adj. /  aláìgbọràn, aláfojúdi.

Disobey verb. /  ṣe àìgbọràn, ṣàfojúdi.

Disobliging adj. /  ni aròró.

Disorder noun. /  ìdàrúdàpọ, rúdurùdu, àrùn.

Disown verb. /  kọ̀, kọ̀ láti gba, yínnù .

Disperse verb. /  túká, fúnká.

Displace verb. /  yí nípò padà.

Display noun. /  fi hàn, àṣehàn.

Dis

Disprove verb. /  àìfaramọ.

Dispute noun. /  ìjiyàn, àríyànjiyàn. verb. / jiyàn sí.

Dissolve verb. /  yọ́, túká, fòpin sí.

Distance noun. /  ọ̀nà jínjìn, jíjìnà, ìtakété.

Distant adj. /  jìnà, jìjín, lókèrè.

Distinction noun. /  ìyàtọ̀, híhàn gbangba.

Distract verb. /  pín níyà, dàláàmú, sọ di asínwín.

Distress noun. /  ìsẹ́, ìpọ́njú.

Distribute verb. /  pín.

Distribution noun. /  ìpínfúnni.

District noun. /  àgbègbè, sàkání, àdúgbò.

Distrust noun. /  àìgbẹ́kẹ̀lé, àìfọkàn-tàn, àìgbáralé.

Disturb verb. /  yọ-lẹ́nu, dí lọ́wọ́.

Disturbance noun. /  ìdílọ́wọ́, ìrúkérudò.

Ditch noun. /  kòtò, ọgbun.

Dive verb. /  lọ sí ìsàlẹ̀ omi, mòòkùn.

Diverse adj. /  yàtọ̀, onírúurú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba