HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Eff
Efficient
adj.
/ ní agbára láti ṣiṣẹ́ laigba àsìkò.
Effort
noun.
/ ìgbìyànjú, ìyànjúagbára, káká, fitafita.
Effuse
verb.
/ tú jáde.
Effusion
noun.
/ itújáde.
Egg
noun.
/ ẹyin.
Eight (8)
noun.
/ ẹjọ, mẹ́jọ.
Eighteen (18)
noun.
/ éjìdínlógún, méjìdìnlógún.
Eighth (8th)
adj.
/ ìkẹjọ.
Either
conj.
/ èyí tàbí èyinì, ọkan nínú méjèjì, yálà.
Eject
verb.
/ lé jáde, tì sóde, ta-nù, bì jáde.
Elaborate
adj.
/ dára púpọ, a ṣe fínnífínní, a fi aápọn ṣe.
Elbow
noun.
/ ìgbọnwọ, ìgúnpá.
Elder
noun.
/ alàgbà, àgbàlagbà, ẹ̀gbọ́n.
Elders
noun.
/ àwọn àgbàgbà.
Elect
verb.
/ yàn, ṣà.
Election
noun.
/ ìṣàyàn, idibo, yíyàn.
Electricity
noun.
/ iná ìgbàlódé, ìtànná.
Elegance
noun.
/ ìdára, ẹwà.
Ele
Elegant
adj.
/ dídára, dídùn, lẹ́wà.
Elementary
adj.
/ ibẹ̀rẹ, ipilẹṣẹ .
Elephant
verb.
/ erin.
Elevation
noun.
/ ìgbélékè, ìgbéga.
Elevator
noun.
/ ẹ̀rọ ìgbé nkan sókè.
Eleven (11)
noun.
/ ọ́kànlá, mọ́kànlá.
Eleventh (11th)
adj.
/ ìkọkànlá.
Eligible
adj.
/ yẹ ní yíyàn.
Eliminate
verb.
/ tí jáde, mú kúrò.
Else
adv.
/ òmíì, òmíràn, bíbẹkọ.
Elsewhere
adv.
/ nibomi.
Elude
verb.
/ fi èrú tàn sílẹ̀.
Elusive
adj.
/ tí a fi èrú tàn sílẹ̀.
Embargo
noun.
/ òfin ìdádúró ìsòwò.
Embark
verb.
/ fi sọ́kọ̀, wọkọ̀.
Embarrass
verb.
/ gọ̀, sú, dààmú.
Embarrassing
adj.
/ dídàmú, gígọ̀, sísú.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.