HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Each
Each
pron.
/ ọkọkan, olúkúlùkù, ẹyọkọkan.
Eager
adj.
/ nítara, níwára.
Eagerly
adv.
/ pẹ̀lú nítara, pẹ̀lú níwára.
Eagle
noun.
/ ọrúkọ ẹyẹ kan tí ọ́ mọ́ ngbé ọmọ adìẹ.
Ear
noun.
/ etí, ṣirì-ọkà.
Earache
noun.
/ etí ríro, etí dídùn.
Early
adj.
/ kùtùkùtù, tẹ́lẹ̀, ní ìbẹ̀rẹ̀.
Earn
verb.
/ pa owó, jẹ, ṣiṣẹ́ owó, rí-gbà.
Earring
noun.
/ òrúka etí, yarini.
Earth
noun.
/ ayé, ilẹ̀, erùpẹ̀.
Earthquake
noun.
/ ilẹ̀ mímì, ìwàrìrì ilẹ̀, ilẹ̀ sísán.
Earthworm
noun.
/ ekòló.
Ease
noun.
/ ìrọra, àìnira, ìdẹra.
East
noun.
/ ìlà oòrùn, gàbasì.
Easter
noun.
/ ọjọ́ àjínde Krístì, àgbènde.
Eastern
adj.
/ nílà-oòrùn.
Eastward
adv.
/ níhà ìlà-oòrùn.
Easy
adj.
/ láìsòro, ní-rọ̀rùn, láìnira.
Eat
Eat
verb.
/ jẹ, jẹun.
Eatable
noun.
/ nkan jíjẹ.
Eavesdrop
noun.
/ ẹnití nfi etí mọ́ ògiri gbọ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀.
Echo
noun.
/ gbohùngbohùn.
Economic
adj.
/ nípa ọrọ̀-ajé.
Economy
adj.
/ mímọ owó tọ́jú.
Ecstacy
noun.
/ ayọ̀ ayọ̀ju, ayọ̀ púpọ̀.
Eczema
noun.
/ kòkòrò tó ma nyún yàn lára.
Edge
noun.
/ ojú ohun èlò, etí nkan.
Edit
verb.
/ ìyọkúrọ̀ tàbí ìfikún nkan bí ìwé kíkọ.
Edition
noun.
/ ṣíṣe ìwé.
Editor
noun.
/ ẹnití nse ìwé fún títẹ̀, olótùú.
Educate
verb.
/ kọ́ lẹkọ, tọ́, kọ́.
Education
noun.
/ ẹ̀kọ́.
Eel
noun.
/ ẹja tógùn tí ara rẹ tínrín.
Effect
noun.
/ èrè, èso iṣẹ, ìyọrísí.
Effective
adj.
/ wúlò, èyí tí yóò níyọrísí.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.