English - Yorùbá Dictionary

Endure

Endure verb. /  rọ́jú, forítì, faradà.

Enemy noun. /  ọ̀tá, oníkeéta.

Energy noun. /  agbára, okun-inú.

Enfetter verb. /  dè ní ẹ̀wọn.

Enforce verb. /  kàn nípá, fagbára ṣe, mú kó lágbára.

Engage verb. /  fi sisẹ́, ba ṣàdéhùn ìgbéyàwó.

Engagement noun. /  ìdána, àdéhùn ìgbéyàwó, ìlérí.

Engine noun. /  ẹrọ, enjìnnì.

Engineer noun. /  ẹnití ó ní ọgbọ́n láti fise ẹrọ enjìnni.

Engrave verb. /  fín, ṣọnà fínfín sí, gbẹ́.

Enjoy verb. /  gbádùn, jayé.

Enjoyment noun. /  ìgbádùn, adùnìjayé, ìdùnnú, ìdùnmọ́.

Enlarge verb. /  fẹ̀, mú-tóbi, fikún, bùmọ.

Enlargement noun. /  ìmútóbi, fífẹ̀, àfikún, ìbùmọ.

Enormous adj. /  títóbi púpọ̀.

Enough adv. /  tó, tẹ́rùn, kárí.

Enquire verb. /  bere, wadi.

Enroll verb. /  fi orúkọ sílẹ̀ láti lọ ilé ìwé gíga.

Enr

Enrollment noun. /  ìforúkọsílẹ̀ nínú ìwé.

Ensure verb. /  ṣe-dájú, mú dájú.

Enter verb. /  wọ, wọlé, wọnú, kọ sínú ìwé, bọ sínú.

Entertain verb. /  ṣe eré, ṣe lálejò, bá-sọ̀rọ̀ múlárayá.

Enthusiasm noun. /  ìtara, akitiyan.

Enthusiastic adj. /  lákitiyan, nítara.

Entire adj. /  gbogbo, ọ̀tọ̀tọ̀, odidi.

Entirely adv. /  pátápátá, bámbám, yányán, gbẹrẹgẹdẹ.

Entrance noun. /  ẹnu ọ̀nà, ojú ọ̀nà, àbáwọlé.

Entry noun. /  ọ̀nà ìwọ̀lú, ohun tì a kọ sínú ìwé.

Envelope noun. /  àpò ìwé, ìbọ̀wé.

Envious adj. /  kún fún ìlara, nílara.

Environment noun. /  àyíká, àdúgbò.

Envy noun. /  ìlara.

Epidemic noun. /  àjàkálẹ̀ àrùn.

Equal adj. /  dọ́gba, rí bákannáà.

Equality noun. /  ìdọgba, ìbádọgba.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba