English - Yorùbá Dictionary

Equ

Equally adv. /  bákannà, dọ́gba-dọ́gba.

Equanimity noun. /  ìbalẹ̀ ọkàn.

Equator noun. /  ìlà àyíká tí ó dá ayé sí méjì lọ́gbọgba.

Equip verb. /  pèsè, ṣe-lọ́ṣọ.

Equipment noun. /  ìpèsè, ìmúra, ìṣelọ́ṣọ.

Equity noun. /  ìṣotítọ́.

Equivalent adj. /  bá mu, bá ṣe dédé.

Era noun. /  ìbẹ̀rẹ̀ sí ka ọjọ́, sanmọni.

Eradicate verb. /  párẹ́, tu gbọ̀ngbọ̀ rẹ̀.

Erase verb. /  pa-rẹ́, pa-run.

Eraser noun. /  ohun ti á fi npa nkan rẹ́.

Erect verb. /  gbé dìde, kọ́lé.

Erection noun. /  ìkọ́lé.

Err verb. /  ṣìṣe, ṣìnà.

Error noun. /  àṣìṣe, èèṣì, ìṣìṣe, ìṣìnà.

Erupt verb. /  ru, tújáde.

Eruption noun. /  ríru jáde, ìtújáde.

Escalate verb. /  ru sókè, se kí ó di nlá.

Esc

Escape noun. /  ìsákúrò nínú ewu, àjàbọ́. verb. / sá jáde.

Escort noun. /  alábò, bò. verb. / se àbò ẹni lọ́nà.

Especially adv. /  pàápàá, àmbòsí.

Essay noun. /  nkan tí a kọ sílẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ pàtàkì, ìdánwò.

Essential adj. /  ṣe pàtàkì, tí a kò lè ṣaláìní.

Establish verb. /  dásílẹ̀, fi lélẹ̀, pinnu, fi kalẹ̀.

Establishment noun. /  ìdásílẹ̀, ìfilélẹ̀, ìpinnu.

Estate noun. /  ohun ìní.

Estimate verb. /  ka iye, sírò, díyelé.

Eternal adj. /  láíláí, ayérayé.

Eternity noun. /  ayérayé, àìlópin.

Evacuate verb. /  kó jáde, jáde kúrò.

Evacuation noun. /  ijáde kúrò, ìsílọ.

Evade verb. /  yẹ ara fún, yẹ-sílẹ̀.

Evaluate verb. /  ṣàgbéyẹ̀wò, gbé léwọ̀n.

Evaporate verb. /  gbẹ́, fà.

Evasion noun. /  àwáwí, yíyẹ̀ sílẹ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba