English - Yorùbá Dictionary

Find

Find verb. /  wá, rí, wá kiri, bá.

Fine adj. /  dára, dùn, owó ìdáràn.

Finger noun. /  ìka ọwọ́.

Finish verb. /  parí, se-tán, yorí.

Finished adj. /  tán, pátápátá.

Fire noun. /  iná.

Firewood noun. /  igi ìdáná.

Firm adj. /  lágbára, le, dúró ṣinṣin, gbọingbọin.

First adj. /  èkíní, níṣàjú.

First born noun. /  àkọ́bí.

Fish noun. /  ẹja. verb. / pẹja.

Fist noun. /  ìkuùkù.

Fit verb. /  se ìbámu, yẹ.

Fitness noun. /  yíyẹ, ìbámu.

Five (5)  noun. /  árùn, márùn.

Fix verb. /  fà-so, mú-dúró, fi-bọ.

Flag noun. /  àsíá, opágun, koríko odò.

Flame noun. /  ọ̀wọ́ iná, ìgbóná okàn, aló iná.

Flap

Flap noun. /  ìgbọn ìyẹ́ pìpì.

Flare noun. /  ohun tí n jó bùlàbùlà.

Flash noun. /  ìkọ sàn, ìmọ́lẹ̀.

Flat adj. /  tẹ, tẹjú, pẹrẹsẹ.

Flatter verb. /  pọn, tàn.

Flavour noun. /  àádùn, ìtọ́wò.

Flaw noun. /  àbúkú, sísán, ìlà.

Fledge verb. /  gún iyẹ́, hùyẹ́.

Flee verb. /  sá, sá-lọ.

Flesh noun. /  ẹran ara.

Fleshy adj. /  kiki ẹran.

Flexible adj. /  rọrùn láti tẹ̀, rọrùn láti lọ̀.

Flight noun. /  ìrín àjò, ìsákúrò nínú ewu, ìsákúsàá, ìsálọ.

Flimsy adj. /  fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́.

Flirt verb. /  ṣiré ìfẹ̀.

Float verb. /  lefó, fó lójú omi.

Flood noun. /  ẹkún omi sísàn, ìkún omi.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba