English - Yorùbá Dictionary

Fell

Fellow noun. /  ẹgbẹ́, ẹnikeji.

Fellowship noun. /  ìdàpọ̀, ìkẹ́gbẹ́.

Female adj. /  obìnrin, abo.

Fence noun. /  ọgbà, ògiri.

Fertile adj. /  léso, lẹtù lójú,lọrá.

Fertilizer noun. /  àjílẹ.

Festival noun. /  ìgbà àsè, àjọ̀dún.

Fetch verb. /  mú wá, gbé wá.

Feud noun. /  ìjà, asọ̀, ààwọ̀, èdè aiyédè.

Fever noun. /  ibà, òtútù.

Feverish adj. /  ni ibà,ni òtútù, ni ara gbígbóná.

Few adj. /  díẹ.

Fewer noun. /  níwọ̀nba.

Fiancée noun. /  àfẹ́sọ́nà.

Fiber noun. /  okùn igi, okùn ewéko.

Fiddle noun. /  dùrù.

Fiddler noun. /  atẹdùrù, onífèrè.

Fidle string adj. /  okùn dùrù.

Fide

Fidelity noun. /  olótọ, ìfaramọ.

Field noun. /  pápá ìsiré.

Fierce adj. /  rorò, múná, gbóná.

Fifth adj. /  ìkarùn, ẹkarùn.

Fight noun. /  ìjà, ogun.

Fighter noun. /  oníjà, jagunjagun.

Figurative adj. /  ni àpẹrẹ.

Figure noun. /  iye.

File noun. /  ìtọ́jú ìwé, irin tí a fi npọ́n àdá, ayùn.

Fill verb. /  kún, tẹ́-lọ́rùn.

Filter noun. /  asẹ́. verb. / sẹ́, ro.

Filth noun. /  ẹgbin, eri, ọbun.

Fin noun. /  lẹbẹ ẹja.

Final adj. /  ti igbẹ̀yin, ti ipari.

Finally adv. /  lákòótán, níparí, lópin ípẹkun, níkẹhìn.

Finance noun. /  owó, ìnáwó. verb. / se ìnáwó.

Financier noun. /  olùtọ́jú owó.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba