English - Yorùbá Dictionary

Forge

Forge verb. /  rọ, lù.

Foregery noun. /  rírọ èké.

Forget verb. /  gbàgbé, sàìrántí.

Forgetful adj. /  sé gbàgbé, nígbàgbé.

Forgive verb. /  dáríjì, foríjì.

Forgiveness noun. /  ìdáríjì, ìfijì, àforíjì.

Form noun. /  ààtò, àwòrán, ìjokò. verb. / mọ, fun.

Formality noun. /  ìse ìdásílẹ̀, àpẹrẹ ìse.

Former adj. /  tiṣaju.

Formerly adv. /  ìgbà, látẹ̀hìnwá, ìṣájú.

Fornicate verb. /  ṣe panṣágà, ṣe àgbere.

Fortnight noun. /  ìgbà ọ̀sẹ̀ méjì.

Fortress noun. /  odi alágbára.

Fortunate adj. /  ṣe oríre, bọ ṣákokò, ṣàgbákò.

Fortune noun. /  ọlá, alábàápàdé, ohun ìní, àbáfú.

Forty (40)  noun. /  ogójì.

Forward adv. /  lọ síwájú, ìsájú, imúra.

Foster child noun. /  ọmọ àgbàbọ́, ọmọ àgbàtọ́.

Foun

Found noun. /  ri, fi ìpilẹ̀, lélẹ̀, dasílẹ̀, tẹ̀dó.

Foundation noun. /  ìpilẹ̀ ilé, ìsọlẹ̀.

Founder noun. /  olùdásílẹ̀.

Fountain noun. /  orísun, ìsun.

Four (4)  noun. /  ẹrin, mẹrin.

Fourteen (14)  noun. /  mẹrinla, ẹrinla.

Fowl noun. /  adìyẹ tàbí ẹyẹ.

Fox noun. /  kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, akátá, alárèkérekè.

Fracture noun. /  dídá egungun.

Fragile adj. /  ẹlẹ́gẹ fífọ́, nkan tí ki pẹ́ fọ́.

Fragment noun. /  erúnrún, ibù, èrún.

Fragrance noun. /  òórùn dídùn.

Fragrant adj. /  olóòrún dídùn, tí nta sánsán.

Frame noun. /  ago ara, ìlànà fèrèsé.

Frank adj. /  sọ òtítọ́ inú jáde.

Fraud noun. /  jìbìtì, ẹtàn, èrú, ayedèrú.

Fraudulence noun. /  itanjẹ, isèrú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba