HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Free
Free
adj.
/ láìdè, aláìnídè.
adv.
/ ọ̀fẹ́.
verb.
/ sọ di ominira.
Freedom
noun.
/ òmìnira.
Freeze
verb.
/ dì.
Freight
noun.
/ ẹrù ọkọ̀.
Freighter
noun.
/ ọkọ̀ àkẹrù.
Frenzy
noun.
/ ìsínwín, ìṣiwèrè.
Frequency
noun.
/ ìgbàkúùgbà.
Frequent
adj.
/ nígbàgbogbo, nígbàkúùgbà.
Frequently
adj.
/ lemọ́lemọ́, léraléra.
Fresh
adj.
/ tútù, titun, àkọ̀tun.
Friday
noun.
/ ijọ́ kẹfà ọsẹ, Jímọ̀h.
Friend
noun.
/ ọ̀rẹ́, ẹnìkejì.
Friendly
adj.
/ ìfanimọ́ra.
Friendship
noun.
/ ìrẹ́, ìrẹ́pọ̀, ìbárẹ́.
Frigate
noun.
/ ọkọ̀ ogun.
Fright
noun.
/ ẹrú, ìfòyà.
Frighten
verb.
/ dẹrùba, dáyà-ja.
Frog
noun.
/ ọ̀pọ̀lọ́.
From
From
prep.
/ lọ́wọ́, kúrò, nínú, láti.
Front
adj.
/ iwájú.
Frost
noun.
/ òtútù níní.
Frosty
adj.
/ ní òtútù, òtútù jọ́jọ́.
Frown
noun.
/ ìbojújẹ́, ìbínú.
verb.
/ bojújẹ́, bínú si.
Frozen
adj.
/ dídì.
Fruit
noun.
/ éso, ọmọ.
Frustrate
verb.
/ bà-jẹ́, yí-po, yẹ̀-pá, sọ di asán.
Frustration
noun.
/ ìbàjẹ́.
Fry
verb.
/ yan nínú epo, dín.
Fugitive
noun.
/ ìsánsá.
adj.
/ lai dúró níbìkan.
Fulfil
verb.
/ mú ṣẹ.
Fulfilment
noun.
/ ìmúṣẹ .
Full
adj.
/ kún.
Fully
adv.
/ ni kikún.
Fume
noun.
/ èéfín, oru.
Fun
noun.
/ iré, ìṣiré, ẹ̀fẹ̀, àwàdà.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.