English - Yorùbá Dictionary

Gar

Gardener noun. /  olùsọgbà, asọgbà.

Garland noun. /  ìtanná ewé.

Garrulous adj. /  aláròyé.

Gash noun. /  ọgbẹ́ nla.

Gasp verb. /  yanu sílẹ̀ gba afẹ́fẹ́.

Gate noun. /  ẹnu ọ̀nà òde, ìlẹ̀kùn.

Gate keeper noun. /  olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà.

Gateway noun. /  àbáwọlé, àbáwọ̀lú, ìwọ̀lú, ojúbodè.

Gather verb. /  kójọ, kópọ sí ibìkan, sà jọ, péjọ, gbá-jọ.

Gathering noun. /  ìkójọ, ìkópọ sí ibìkan, ìpéjọ , ìgbá-jọ.

Gauge noun. /  ọ̀pá ìdíwọ̀n.

Gender noun. /  imọ akọ tàbí abo yàtọ.

General adj. /  wọ́pọ̀, ti gbogbo ènìyàn.

Generally adv. /  nígbàkúgbà, lákòpọ, lákolù.

Generate verb. /  bí, bẹ̀rẹ̀, mú jáde, dá sílẹ̀.

Generation noun. /  ìran.

Generosity noun. /  inú rere.

Generous adj. /  nínú rere.

Gen

Genius noun. /  olóye, amòye, iwin.

Gentle adj. /  ní ìwà pẹ̀lẹ́, se jẹ́jẹ́.

Gently adv. /  pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́, rọra, lẹ́sọ̀lẹ́sọ̀, kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́.

Genuine adj. /  lótítọ, láìṣẹtàn, ojúlówó.

Germ noun. /  èèhù, orísun, kòkòrò.

Gesture noun. /  ìsesí, ìwo.

Get verb. /  ní, rígbà, gbà.

Geyser noun. /  orísun omi gbígbóná tí nrú láti inú ilẹ̀ wá.

Ghost noun. /  òkú ti nda ẹru ba alaye ènìyàn, ẹ̀mí, iwin.

Giant noun. /  òmìrán, asígbọnlẹ̀.

Gift noun. /  ẹbùn, ọrẹ.

Giggle verb. /  rín ẹ̀rín kékeré.

Gill noun. /  ẹ̀rẹ̀kẹ́ ẹja.

Giraffe noun. /  àgùnfọn.

Girl noun. /  ọmọbìnrin.

Give verb. /  fi fún, fi bùn, jìn.

Glacier noun. /  yìnyín nlá gbalasa.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba