HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Fun
Function
noun.
/ ìlò, agbára, òye.
Fund
noun.
/ ìkójọpọ̀ owó.
Fundament
noun.
/ ìdí.
Fundamental
adj.
/ ti ìpilẹṣẹ, pàtàkì.
Funeral
noun.
/ ìsìnkú.
Fungus
noun.
/ olú igi, olú.
Funnel
noun.
/ àtìrọ, arọ, ìrọ, iho efin.
Funny
adj.
/ oníyẹ̀yẹ́, pa ni lẹ́rin.
Fur
noun.
/ irun múlọ́múlọ́.
Furious
adj.
/ tìbínù.
Furnace
noun.
/ iléru.
Furnish
verb.
/ pèsè fún.
Furrow
noun.
/ aparo.
Further
adv.
/ ṣíwájú, lókèrè.
Fury
noun.
/ ìkannú, ìbínú, ìrunú.
Fuss
noun.
/ ìrọ́kẹ́kẹ́, aisimi.
Futile
adj.
/ lasan, laiwulo.
Future
noun.
/ ti ìgbà tí mbọ̀, ti ẹ̀yìn ola, ti ọjọ́ iwájú.
Gain
Gag
noun.
/ asọ ìrépé tí a fi bọ ènìàn lẹ́nu ko mọ ba sọ̀rọ̀.
Gain
noun.
/ èrè, ìfà.
verb.
/ jèrè, rí gbà, rí se.
Gainsay
verb.
/ riwisi, sọrọ òdì si.
Gaiter
noun.
/ aṣọ ìwésẹ̀.
Gala
noun.
/ ìdárayá, àríyá.
Gale
noun.
/ afẹ́fẹ́ líle, atẹ́gùn líle, iji.
Gamble
verb.
/ ta tẹ́tẹ́.
Gambler
noun.
/ atatẹ́tẹ́.
Gambling
noun.
/ tẹ́tẹ́ títa.
Game
noun.
/ iré, ìṣ iré, ẹyẹ tí ọdẹ pa.
Gander
noun.
/ akọ pẹ́pẹ́yẹ.
Gang
noun.
/ ẹgbẹ́ tí ó so wọ́pọ̀ láti se nkan.
Gaol
noun.
/ ilé ẹ̀wọn, ilé túbú.
Gap
noun.
/ ihò, ẹlà, ìsán, àfo.
Garage
noun.
/ ilé ìpamọ́ ọkọ̀, ilé àtúnse ọkọ̀.
Garbage
noun.
/ ìdọ̀tí.
Garden
noun.
/ ọgbà.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.