English - Yorùbá Dictionary

Gori

Gorilla noun. /  ìnàkí.

Gospel noun. /  ìyìn rere, ìtàn ìgbé ayé Jésù, ọ̀rọ̀ òdodo.

Gossip noun. /  ọ̀rọ̀ ẹhìn, ìsọ̀rọ̀ asán, òfófó.

Govern verb. /  jọba, ṣàkóso, ṣolórí, ṣètọ́jú.

Governess noun. /  olùkọ́ni obinrin.

Government noun. /  ìjọba, àkóso ìlú.

Governor noun. /  alákòóso ìlú, baálẹ, olórí, gómìnà.

Grab verb. /  já gbà.

Grace noun. /  ore-ọ̀fẹ́, ojú rere, ànfàní.

Graceful adj. /  dídára, lẹ́wà.

Gracious adj. /  olóre-ọ̀fẹ́, aláàánú.

Grade noun. /  ipò.

Gradually adj. /  díẹdíẹ.

Graduate verb. /  to fínífíní, gba oyè ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, wọn.

Graduation noun. /  ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ kíkà.

Grain noun. /  wóró irúgbìn ọkà, àgbàdo.

Grammar noun. /  ìmọ ìlò ọrọ dájúdájú.

Grammatical adj. /  mímọ̀ ìlò ọrọ dájúdájú.

Gra

Grand adj. /  tóbi, níyìn, lọ́lá.

Granddaughter noun. /  ọmọ ọmọ lóbìnrin.

Grandfather noun. /  bàbá bàbá ẹni, bàbá ìyá ẹni.

Grandmother noun. /  ìyá bàbá ẹni, ìyá ìyá ẹni.

Grandson noun. /  ọmọ ọmọ lọkùnrin.

Granite noun. /  òkúta akọ dúdú.

Grant verb. /  fi fún, fi jín, gbà. noun / ohun tí a fifúnni.

Grape noun. /  orúkọ èso kan.

Grasp verb. /  dìmú, fọwọ́ gbá mú.

Grass noun. /  koríko.

Grateful adj. /  lọpẹ, more.

Gratitude noun. /  ìdúpẹ́, ìmore.

Grave noun. /  ibojì, isà òkú. verb. / gbẹ́, fín, ṣọnà fínfín si.

Gravel noun. /  òkúta wẹ́wẹ́, òkúta wẹrẹ, yanrìn.

Gravestone noun. /  òkúta orí ibojì.

Graveyard noun. /  itẹ òkú.

Gravity noun. /  ìwà àgbà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba