English - Yorùbá Dictionary

Gravy

Gravy verb. /  omi ọbẹ̀, omitoro.

Grease noun. /  ọ̀rá.

Greasy adj. /  kún fún ọ̀rá.

Great adj. /  tóbi, nlá, pọ.

Greatness noun. /  títóbi.

Greed noun. /  ìwọra, ojúkòkòrò.

Greedy adj. /  níwọra, lójúkòkòrò.

Green adj. /  aláwọ̀ ewé.

Greenhouse noun. /  ilé ìtọ́jú nkan ọgbìn.

Greet verb. /  kí, yọ̀ mọ.

Greeting noun. /  ìkíni, iyọ̀mọni.

Grief noun. /  ìbànújẹ́, ẹ̀dùn.

Grievance noun. /  ohun ìbanújẹ́.

Grieve verb. /  bànínújẹ, mú ní kẹ́dùn.

Grim adj. /  korò, rorò.

Grime noun. /  érí. verb. / fi érí yi.

Grin noun. /  ẹ̀rín àìdénú, ẹ̀rín iyangi, ẹ̀rín ẹ̀gan.

Grind verb. /  lọ̀, pọ́n.

Grip

Grip noun. /  ìgbámú. verb. / gbámú, dìmú sinsin.

Groan noun. /  ìkérora, gbígbin. verb. / kérora.

Groin noun. /  kòtò itan.

Groom noun. /  olùtọ́jú ẹsin, ọkọ-ìyàwó.

Groove noun. /  ihò ìtẹ̀bọ̀.

Ground noun. /  ilẹ̀, ìpìlẹ̀, orísun.

Group verb. /  àkójọpọ̀, ìdìpọ̀.

Grove noun. /  igbó kékeré, igbó suru.

Grow verb. /  hù, so, dàgbà.

Growl verb. /  ké.

Growth noun. /  ìdàgbàsókè, dídàgbà ènìyàn, híhù.

Grub noun. /  kòkòrò ìdin.

Grumble verb. /  kùn, kùn sínú.

Grumpy adj. /  oníkanra.

Grunt verb. /  kùn bí ẹlẹ́dẹ̀.

Guarantee noun. /  onígbọwọ́, ẹ̀rí.

Guard noun. /  abo, ìṣọ́, olùṣọ́. verb. / ṣọ dábòbò.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba