HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Aa
Aback
adv.
/ ìyàlẹ́nu, lójijì, láiròtẹ́lẹ̀.
Abandon
verb.
/ fi sílẹ̀, kọ̀sílẹ̀.
Abandoned
adj.
/ fifisílẹ̀, kikọ̀sílẹ̀ pátápátá.
Abandonment
noun.
/ ifisílẹ̀, ikọ̀sílẹ̀ pátápátá.
Abate
verb.
/ dínkù, fàsẹ́hìn, dáwódúró diẹ.
Abatement
noun.
/ ídínkù, ifàsẹ́hìn, idáwódúró diẹ.
Abbey
noun.
/ ilé àkọ́mọ́ iléìjọ́sìn.
Abbreviate
verb.
/ gé kúrú, ṣẹ́kù.
Abbrevation
noun.
/ ìgékúrú, ìṣẹ́kù.
Abdicate
verb.
/ bọ́ oyè sílẹ̀.
Abdication
noun.
/ ìbọ́ oyè sílẹ̀.
Abdomen
noun.
/ ikùn.
Abduct
verb.
/ gbé sálọ , fà kúrò.
Abduction
noun.
/ ìgbé sálọ , ìfà kúrò.
Abeyance
noun.
/ ìdádúró.
Abhor
verb.
/ kórira.
Abhorrence
noun.
/ ìkórira.
Abide
verb.
/ bá gbé.
Ability
Ability
noun.
/ agbára, òyé.
Abjuration
noun.
/ ìbúra, ìgégun.
Abjure
verb.
/ fi-bú, fí gégun.
Ablaze
adv.
/ gbiná.
Able
adj.
/ lè, lágbára.
Ablution
noun.
/ ìfomí-wẹnu pẹ̀lú ọwọ́ pẹ̀lú ojú, (àlùwàlá).
Abnormal
adj.
/ ṣàjèjì, abàmì.
Aboard
adv.
/ nínú ọkọ̀, sínú ọkọ̀.
Abode
noun.
/ ìbùgbé, ibùjókò.
Abolish
verb.
/ pa-rẹ́, sọ-dasán, sọ-dòfo.
Abolition
noun.
/ iparẹ́, isọ-dasán, isọ-dòfo.
Abominable
adj.
/ rinilara, lẹ́gbin.
Abomination
noun.
/ ẹgbin, ohun irira.
Aborigines
noun.
/ ọmọ-ìbílè, onílẹ̀.
Abortion
noun.
/ ìsẹ́yún, ṣíṣẹ́ oyún.
Abortive
adj.
/ jásí asán.
Abound
verb.
/ pọ̀, di pípọ̀.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.