English - Yorùbá Dictionary

Ab

About prep. / nípa tí, yíká, nítòsí, létí.

Above prep. / ga jùlọ , pọ jùlọ .

Abridge verb. / dínkù, ké kúrú.

Abroad adv. / lóde, lẹhìn odi, ìdálẹ̀.

Abrogate verb. / mú kúrò, sọ di asán.

Abrupt adj. / lójijì, laimọ̀tẹ́lẹ̀.

Abscond verb. / sápamọ́, sálọ fun iyà.

Absconder noun. /  asápamọ́, isansa.

Absence noun. / àisí-nílé.

Absent adj. / kò sí, kò wá.

Absolutely adj. / pátápátá.

Absolution noun. / ìdáríjì, ìfijì-ẹ̀ṣẹ̀.

Absolve verb. / dáríjì, fijì, tú-sílẹ̀.

Absorb verb. / mì, lá, fà-mu,mu tán.

Abstain verb. / fà-sẹ́hìn, takété.

Abstinence noun. / aìjẹun, àwẹ̀.

Abstract verb. / mú kúrò, fà jáde.

Absurd adj. / ṣàjeji, ṣaìbọgbọnmu.

abundance

Abundance noun. / ọ̀pọ̀ .

Abundantly adv. / lọ́pọ̀lopọ́ , jìgbìnni, gègèrè.

Abuse verb. / lò nílòkúlò, bú.

Abusive adj. / èébú.

Academic adj. / akadá.

Academy noun. / ilé ẹ̀kọ́ giga.

Accede verb. / gbà fún, fohùnsí, kà-kún.

Accelerate verb. / mú yára, mú lọ síwájú.

Acceleration noun. / ìyára.

Accelerator noun. / ohun ìmúyára.

Accend verb. / tinábọ̀.

Accent noun. / àmì ohùn.

Accept verb. / gbà, tẹ́wọ́gbà.

Acceptable adj. / gbígbà, títẹ́-wógbà.

Acceptance noun. / ìtẹ́wógbà.

Access noun. / àyè, ọ̀nà.

Accessible adj. / fún láyè.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba