English - Yorùbá Dictionary

Pro

Provide verb. /  pèsè sílẹ̀, pèsè fún, múwá, fihàn.

Province noun. /  ìgbèríko, ojú iṣẹ.

Provincial adj. /  ti agbègbè ìlú.

Provisional adj. /  tí a pèsè tẹ́lẹ̀.

Provoke verb. /  tọ, mú bínú, yọ lẹ́nu, fìtínà.

Proximity noun. /  agbègbè, ìtòsí, etí.

Proxy noun. /  ìrọ́pò, ìdúró fun, ìgbọ̀wọ́.

Prudence noun. /  òye, ọgbọ́n.

Prudent adj. /  amòye, ọlọ́gbọ́n.

Pub noun. /  ilé ìmutí.

Puberty noun. /  àkókò èwe ọkùnrin tàbí obìnrin.

Public adj. /  ti gbogbo ènìyàn.

Publication noun. /  ìkéde, ìtẹ̀wé sóde, ìfilọ̀.

Publicly adv. /  ni gbangba.

Publish verb. /  sọ di mímọ̀, kéde, tẹ̀ ìwé fún títà, wí kiri.

Publisher noun. /  aṣèwétà, atẹ̀wétà.

Publishing noun. /  ìsọ di mímọ̀, ìkéde, ìṣèwétà, ìtẹ̀wétà.

Puddle noun. /  kòtò kékeré.

Pul

Pull verb. /  fà.

Pullet noun. /  ọmọ adiẹ.

Pulley noun. /  ohun ti afí ngbe nkan wúwo sókè.

Pulpit noun. /  àga ìdúró wàsù.

Pulsate verb. /  lù kìkìkì.

Pulse noun. /  ìlù kìkì ọkàn, ìsọkúlú igbáyà.

Pump noun. /  ẹrọ ìfa omi láti inú ilẹ̀. verb. / fà sókè, fà sínú.

Pumpkin noun. /  elégede.

Punch noun. /  lílù ihò si. verb. / lù ihò, lù, kàn lẹ́sẹ̀.

Punctilious adj. /  kíyèsí nkan kíníkíní.

Punctual adj. /  ṣe lákókò.

Punctuality noun. /  iṣe nkan lákókò.

Punctually adv. /  lákókò gan.

Punctuate verb. /  fi àmì si ìwé kíkà.

Puncture noun. /  ihò kékeré.

Punish verb. /  jẹ́ níyà.

Punishment noun. /  ìyà, ìjìyà, ìjẹníyà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba