English - Yorùbá Dictionary

Pup

Pupil noun. /  ọmọ ilé ìwé, akẹkọ, inú ẹyin ojú.

Puppy noun. /  ọmọ ajá.

Purchase verb. /  rà. noun. / ohun ti a rà.

Pure adj. /  mọ́, dá ṣáká, funfun, ní ìwà àìlábàwọ́n.

Purge verb. /  wẹ̀ mọ́, wẹ̀.

Purification noun. /  ìwẹ̀nimọ́.

Purifier noun. /  aláwẹ̀mọ́.

Purify verb. /  sọ́ di mímọ́.

Purity noun. /  ìwá mímọ́, mímọ́.

Purloin verb. /  jí jalè.

Purloiner noun. /  olè.

Purple adj. /  àwọ̀ àlùkò.

Purport noun. /  ìtumọ̀, ìdí ìtorí.

Purpose noun. /  èrò, ohun tí a nlépa.

Purposeful adj. /  ti ànfàní, tí o ní ìpinnu.

Purr verb. /  kùn bi ológìní.

Purser noun. /  onítọju owó nínú ọkọ̀.

Pursue verb. /  lépa, sáré lé.

Pur

Pursuit noun. /  ìlépa, ìtẹ̀lé.

Purtenance noun. /  ìkópọ̀ inú ẹran.

Purvey verb. /  ra onjẹ sílẹ̀, pèsè sílẹ̀ fun.

Purveyor noun. /  olùtà ohun jíjẹ .

Pus noun. /  ọyún.

Push noun. /  ìtari,ti síwájú. verb. / tì, tari.

Pushy adj. /  bẹ, abẹbẹlúbẹ.

Put verb. /  fi sí, fi lé.

Putrefy verb. /  bà jẹ́, ra.

Putrid adj. /  rírà, bíbàjẹ́.

Putty noun. /  ẹmọ, ate.

Puzzle noun. /  ìsòro, ìsújú, ìrújú, eré ìrújú.

Puzzling adj. /  rírújú, ìrúnilójú.

Pygmy noun. /  aràrá.

Pyjamas noun. /  aṣọ àwọ̀sùn.

Pyre noun. /  ikójọ igi láti fi sun okú.

Python noun. /  òjòlá.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba