English - Yorùbá Dictionary

Pat

Patrol noun. /  olùsọ́. verb. / yí ká láti dabobo.

Pattern noun. /  àpẹrẹ, àwòrán.

Pause noun. /  ìdúró, ìdákẹ́, ìsimi.

Pave verb. /  fi òkúta tẹ́.

Pavement noun. /  pèpéle ti a fi òkúta tàbí ohun miran tẹ́.

Paw noun. /  èékánná ẹranko, ìkùkù.

Pawpaw noun. /  ìbẹ́pẹ.

Pay verb. /  san owó.

Payable adj. /  sísan.

Payment noun. /  ìsanwó.

Peace noun. /  àlàáfíà, ìfàyà balẹ̀.

Peaceful adj. /  lálàfíà, onísùrù, onílàjà.

Peak noun. /  orì òkè, ṣónṣó.

Pedal noun. /  ìfẹsẹ̀tẹ̀.

Pedestal noun. /  ìpìle.

Pedestrian noun. /  onírìnkiri.

Peel noun. /  èpo. verb. / bó, hó, bó èpo.

Peep verb. /  bẹ̀ wò. noun. / ìbẹ̀wò, ìyọjúsí.

Pen

Pelvis noun. /  ìbàdí.

Pen noun. /  kálámù.

Penalty noun. /  ìjìyà, ìyà.

Pendant noun. /  ohun ọ̀ṣọ́ ọrùn .

Penetrate verb. /  wọnú, làkọjá, làjá.

Penis noun. /  okó.

Pension noun. /  owó ìsimi lẹ́nu iṣẹ́.

People noun. /  ènìyàn.

Pepper noun. /  ata.

Per prep. /  láti.

Perceive verb. /  rí, fiyèsí, wòye.

Perfect adj. /  pé, pípé, ànítán. verb. / mú pé, se tán.

Perfection noun. /  pipe, ìṣepé, àìlábàwọ́n, àìlábùkù.

Perform verb. /  ṣe, mú ṣe.

Performance noun. /  ìṣe, ìmúṣe, eré.

Perhaps adv. /  bóyá.

Perimeter noun. /  àgbègbè.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba