English - Yorùbá Dictionary

Par

Parallel noun. /  ìjọra, ifarawe. adj. / tí ó jọra.

Parasite noun. /  àfòmọ́, onírárà.

Parasol noun. /  igborun kékeré ti àwọn obinrin.

Parcel noun. /  ẹrù kékeré.

Pardon noun. /  ìdáríjì. verb. / dáríjì.

Pardonable adj. /  dìdáríjì.

Parent noun. /  òbí.

Park noun. /  ọgbà nlá fún ìsiré gbogbo ènìyàn.

Parliament noun. /  ìgbìmọ̀ ọba.

Parole noun. /  ọ̀rọ̀ ẹnu, ọ̀rọ̀ ọla.

Parrot noun. /  ayékòt ọ́, odídẹrẹ́.

Part noun. /  apá kan, ìpín. verb. / pín, ya.

Partake verb. /  bá pín.

Partial adj. /  ní ojúsájú, ti apá kan.

Participant noun. /  oníbàpín.

Participate verb. /  bá pín.

Participation noun. /  ibápín.

Particular adj. /  pàtàkì, yẹ fún.

Par

Particularly adv. /  ní pàtàkì, pẹ̀lúpẹ̀lú.

Partition noun. /  ìpín, ìlà.

Partner noun. /  alábàṣiṣẹ́, ẹnìkejì.

Party noun. /  ẹgbẹ́, apá kan.

Pass verb. /  kọjá. noun. / ìwé ìwọlé, ọnà lárín òkè méjì.

Passage noun. /  ọnà, àjò lójú omi.

Passenger noun. /  èrò.

Passion noun. /  ìwà, ìtara, ìbínú, inúfùfù.

Passionate adj. /  rúnú, ní inú fùfù, nítara.

Passive adj. /  nírẹ̀lẹ̀, pelú sùúrù.

Past adj. /  kọjá, àtijọ́, níkẹhìn. prep. / lẹ́hìn.

Pastor noun. /  oníwásù, àlúfà.

Pat verb. /  fi ọwọ́ lù jẹ́jẹ́.

Pate noun. /  àwùjẹ̀ orí.

Path noun. /  ọnà, ípa ọnà.

Patience noun. /  sùúrù, ìrọ́jú.

Patient adj. /  ní sùúrù, láìkánjú. noun. / aláìsàn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba