HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Rec
Reclaim
verb.
/ gbà padà, tún gbà, mú padà.
Recline
verb.
/ fara tì, fara rọ̀.
Recognition
noun.
/ ìmọ, ìjẹ́wọ́, ìrántí, ìkàsí, ìfipè.
Recognize
verb.
/ mọ̀, jẹ́wọ́, rántí.
Recommend
verb.
/ yìn, ṣọ̀rọ̀ ẹnìkan ní rere.
Reconsider
verb.
/ tún rò, tún wádi lẹkejì.
Reconstruct
noun.
/ tún kọ́.
Reconstruction
noun.
/ àtúnkọ́.
Record
noun.
/ ìwè ìpamọ́ owó.
verb.
/ kọ, se títẹ̀ orin.
Recover
verb.
/ bọ́lọ́wọ́ àìsàn, gbà padà.
Recovery
noun.
/ ìwòsàn, ìmúláradá, ìgbàpadà.
Recreation
noun.
/ ìdárayá, ìsọjí.
Recruit
verb.
/ gbà sí nú ẹgbẹ́, gbà sí nú iṣẹ́.
Rectangle
noun.
/ onígun mẹ́rin.
Rectify
verb.
/ tún se, mú bọ sípò.
Recuperate
verb.
/ sọjí, mú bọ sí ipò.
Recurrence
noun.
/ ìpadà.
Recycle
verb.
/ tú lọ̀.
Red
Redeem
verb.
/ dá sílẹ̀, rà padà.
Reduce
noun.
/ dín kù, bù kù.
Reduction
noun.
/ ìdínkù, ìbùkù.
Reef
noun.
/ òkúta nísàlẹ̀ òkun.
Refer
verb.
/ fi lọ, gbé padà, tọ́ka sí.
Referee
noun.
/ alábójútó, onílàjà, ẹnití a fi ọ̀ràn lọ̀.
Reference
noun.
/ ìjúwe, ìfilọ̀.
Refil
verb.
/ tún fi kún.
Refine
verb.
/ yọ èrí kúrò, yọ, dán wò.
Reflect
verb.
/ tàn ìmọ́lẹ̀ sí, ronú jinlẹ̀, mú àbùkù bá.
Reform
noun.
/ àtúnse.
Refresh
verb.
/ tù lára, mú lára yá.
Refuge
noun.
/ àbò, ibi isádi, ibi ìsásí, ibi àsálà.
Refugee
noun.
/ ẹnití ó sálọ sí ilẹ̀ míràn fún àbò.
Refund
verb.
/ san padà.
noun.
/ àsan padà.
Refusal
noun.
/ kíkọ̀, àìgbà.
Refuse
verb.
/ kọ, dù.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.