English - Yorùbá Dictionary

Rat

Rattle verb. /  pariwo, mí pẹkẹpẹkẹ, kígbe.

Ravage verb. /  sọ́ di ahoro, parun, bàjẹ, fi sòfò.

Ravine noun. /  àlàfo jíjìn.

Raw adj. /  tutù, àìsè.

Ray noun. /  ìtànsan ìmọ́lẹ̀.

Razor noun. /  abẹ ìfárí.

Reach verb. /  dé, nà, fi kàn.

React verb. /  fèsì.

Read verb. /  kà, kàwé.

Reader noun. /  akàwé.

Reading noun. /  iwé kíkà.

Ready adj. /  múra, se tán, yá.

Real adj. /  tòtọ́, dájú, lódodo, ojúlówó.

Realist noun. /  ojúlówó ènìyàn.

Reality noun. /  òtítọ́, òdodo.

Realize verb. /  mú ṣe, mú ṣe òtítọ́, mọ̀ ní ọ̀ràn.

Really adv. /  dájúdájú, nítòtọ́, lódodo, pàtó.

Rear noun. /  ẹyìn. adj. / lẹ́yìn.

Rea

Rearrange verb. /  tún tò.

Reason noun. /  ìdí, ìtorí, nípa, ọgbọ́n èrò orí.

Reasonable adj. /  tí ó tọ, nídí, níwọ̀ntúnwọ̀nsí, nítumọ̀.

Rebel noun. /  ọlọ̀tẹ̀.

Rebuild verb. /  tún kọ́, tún m ọ́.

Recall verb. /  pè padà, mú wá sí ìrántí.

Recapture verb. /  tún mú lẹ́rú.

Recede verb. /  fà sẹ́hìn, padà sẹ́hìn.

Receive verb. /  gbà, rí gbà.

Recent adj. /  ní titun.

Recently adv. /  ṣẹ̀ṣẹ̀.

Recipe noun. /  apéjúwe.

Recipient noun. /  olùgbà.

Reciprocal adj. /  ṣe pàdà, pàsípàrọ̀.

Reciprocate verb. /  ṣe pàsípàrọ̀.

Recite verb. /  àkọ́sórí, ka iwé ní gbangba.

Reckless adj. /  láìbìkítà, àìlánìyàn, jágbajàgba.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba