English - Yorùbá Dictionary

Rel

Reliable adj. /  se gbẹ́kẹ̀lé.

Relief noun. /  ìrànlọ́wọ́, ìtìlẹ́hìn.

Relieve verb. /  ràn lọ́wọ́, dẹ̀ lára, dá padà.

Religion noun. /  ìsìn, ẹ̀sìn.

Religious adj. /  olùfọ́kànsín.

Relinquish verb. /  fi sílẹ̀, kọ sílẹ̀.

Relish noun. /  adùn, ìtọ́wọ̀ dídùn.

Relocate verb. /  kó kúrò, lọ sí ibòmíràn.

Reluctance noun. /  àìfẹ́, ifatikọ.

Reluctant adj. /  se àìfẹ, se tìkọ̀, lọ́ra.

Reluctantly adv. /  pẹ̀lú ìlọ́ra, tìkọ̀tìkọ̀.

Rely verb. /  simi lé, gbẹ́kẹ̀le.

Remain verb. /  kù, dúró.

Remainder noun. /  ìyókù.

Remaining adj. /  ìyókù.

Remark verb. /  fiyèsí, wipe, sọ̀rọ̀.

Remarkable adj. /  ìyanu, lókìkì, àràbárà.

Remedy noun. /  àtúnṣe.

Rem

Remember verb. /  rántí, níran.

Remembrance noun. /  ìrántí, ìníran.

Remind verb. /  rán létí, sí létí.

Remit verb. /  san padá, fi jì.

Remittance noun. /  owó tí a fi ránṣẹ́ sí òkèrè.

Remorse noun. /  àbámọ̀, àròkàn.

Remorseful adj. /  se àròkàn.

Remote adj. /  jìnnà.

Removable adj. /  tí a lè yí padà, tí a lè mú kúrò.

Remove verb. /  ṣí ipò padà, múkúrò.

Render verb. /  fí fún, san fún.

Rendezvous noun. /  ibi àbò, ibi ìpàdé.

Renew verb. /  ṣọ di titun, tún ṣe, tun jí.

Renewal noun. /  ìsọ́di titun, ìtúnṣe.

Renovate verb. /  sọ́ di titun.

Renovation noun. /  ìtúnṣe, ìsọ́di titun.

Rent noun. /  owó-ilé, háyà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba