English - Yorùbá Dictionary

Rep

Repair noun. /  ìtúnṣe. verb. / túnṣe, tún fi sípò.

Repay verb. /  san padà.

Repayment noun. /  ìsan padà.

Repeal noun. /  ìmúpadà, àpèpadà. verb. / mú padà.

Repeat verb. /  tún sọ, tún wí, tún kà.

Repel noun. /  le padà sẹ́hìn.

Repent verb. /  ronú pìwàdà.

Repentance noun. /  ìronú pìwàdà.

Repetition noun. /  àtúnwí, àwítúnwí, àsotúnsọ.

Replace verb. /  mú padà sípò, san padà, fi dípò.

Replacement noun. /  ìfidípò.

Reply noun. /  ìdáhùn, èsì. verb. / dálóhùn, fèsì.

Report noun. /  ìròyìn. verb. / ròyìn.

Reporter noun. /  oníròyìn.

Represent verb. /  dúró nípò ẹlòmíràn, asojú fún ni.

Representation noun. /  àwòrán, ìmúwá síwájú.

Representative noun. /  aṣojú ẹni, adúró ni ipò ẹni.

Repress verb. /  kì wọ̀, kì mọ́lẹ̀, ṣẹ́gun.

Rep

Reprimand noun. /  ibáwí. verb. / báwí púpọ̀.

Reprint verb. /  tún ìwé tẹ̀.

Reprisal noun. /  ìgbẹ̀san.

Reproduce verb. /  tún mú wá, tún bí jáde.

Reproduction noun. /  ìbí sí, àtúnmú jáde.

Reptile noun. /  ẹranko tí nfí àyà fà.

Request noun. /  ẹ̀bẹ̀, ìbérè. verb. / bẹ̀, bèrè.

Requirement noun. /  ohun tí a fẹ.

Rescue noun. /  ìyọ nínú ewu, ìgbàsílẹ̀. verb. / yọ nínú ewu.

Research noun. /  ìwádí. verb. / se ìwádi.

Resemblance noun. /  ìjọ́ra, jíjọ.

Resemble verb. /  jọ, dàbí, fi wé.

Reservation noun. /  ìfipamọ́.

Reserve verb. /  fi pamọ́.

Reside verb. /  gbé ibì kan.

Residence noun. /  ibùgbé, ilé.

Resident noun. /  olùgbé.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba