English - Yorùbá Dictionary

Swe

Swerve verb. /  ya kúrò lójú ọna.

Swift adj. /  yára, yáṣẹ́, kánkánkán.

Swiftly adv. /  yárayára, kiakia.

Swim verb. /  lúwẹ̀, wẹ̀.

Swimmer noun. /  òmùwẹ̀, ẹnití nlú wẹ̀.

Swindle noun. /  ìrẹ́jẹ.

Swindler noun. /  arẹ́nijẹ.

Swing verb. /  rọ̀ lófurúfú.

Switch noun. /  ìpàrọ̀. verb. / se ìpàrọ̀, tàn.

Swollen adj. /  wú, wíwú sókè.

Swoon noun. /  ìdákú, oyi.

Swoop noun. /  bẹ́ le lórí, mú gírí.

Sword noun. /  idà.

Swordfish noun. /  ẹja onídà.

Swordsman noun. /  ẹnití nlo idà.

Sworn adj. /  timọtimọ. verb. / mú búra.

Syllable noun. /  ègé ọ̀rọ̀ kan, gbolohun ọ̀rọ̀.

Syllabus noun. /  ìwé ìlànà ẹ̀kọ́.

Sym

Symbol noun. /  àmì, àpẹrẹ.

Symbolical adj. /  lápẹrẹ, lámì.

Symbolize verb. /  fi ṣe àpẹrẹ, fi ṣe àmì.

Symmetry noun. /  ìṣedédé, ìdọ́gba.

Sympathetic adj. /  bíbákẹ́dùn.

Sympathiser noun. /  abánikẹ́dùn, abánidárò.

Sympathize verb. /  ba ṣe ìdárò, ba kẹ́dùn.

Sympathy noun. /  ìbáṣedárò, ìbákẹ́dùn.

Symphony noun. /  ìrẹ́pọ̀, ìró ohun púpọ̀.

Symptom noun. /  àmí àrùn, àpẹrẹ.

Synagogue noun. /  ilé ìsìn àwọn Juu.

Syndrome noun. /  àwọn àmì ìsàjèjì.

Synonym noun. /  ọ̀rọ̀ méjí tàbí mẹta tí ó ní ìtúmọ̀ kanna.

Synonymous adj. /  jẹ bakanna pẹ̀lú.

Synopis noun. /  àkópọ̀.

System noun. /  ètò, ìmọ̀, ọ̀nà, ìlànà.

Systematic adj. /  gẹ́gẹ́ bí ti ìlànà, lẹ́ṣẹlẹṣẹ, létòlétò.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba