HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Tab
Table
noun.
/ àga tábìlì, eto.
Tablecloth
noun.
/ aṣọ ìtẹ́lórí tábìlì.
Tabloid
noun.
/ ìwé ìròyìn kékeré pẹ̀lú àwòrán tó pọ̀.
Tacit
adj.
/ gbà laifọhun.
Tack
noun.
/ ìsó kékeré.
verb.
/ sọ mọ, di mọ.
Tackle
verb.
/ kojú rẹ̀ láti gbà , bẹ̀rẹ̀sí ṣe nkan .
Tact
noun.
/ ọgbọ́n láti ma sẹ yan, ìmọ̀.
Take
verb.
/ ṣe, rà, rí gbà, ní.
Tale
noun.
/ ìtàn, àlọ́.
Talent
noun.
/ ẹ̀bùn Ọlọ́run, ẹ̀bùn àbínibí.
Talk
noun.
/ ọ̀rọ̀ ṣíṣọ.
verb.
/ sọ, ṣọ̀rọ̀, wí, fọhùn.
Talkative
adj.
/ aláròyé.
Tall
adj.
/ gùn, gíga, gàgàrà.
Tame
verb.
/ tù lójú.
Tamper
verb.
/ tọwọbọ laiyẹ, fi ọwọ́ kan.
Tangle
noun.
/ kókó, ìdíjú, ìdamún, ìdàrú.
Tank
noun.
/ àgbá nlá.
Tanker
noun.
/ ọkọ̀ omi.
Tar
Tar
noun.
/ ọ̀dà.
verb.
/ fi ọ̀dà kun.
Target
noun.
/ àmì fún ìbọn títa, ìpinu lìti dé bẹ̀.
Tariff
noun.
/ owò ọjà rírà, ìdíyelé nkan.
Task
noun.
/ iṣẹ́.
Taste
noun.
/ ìtọ́wò.
verb.
/ tọwò.
Tasteful
adj.
/ ládùn, dùn.
Tasteless
adj.
/ láiládùn.
Tasty
adj.
/ àdídùn, ládùn.
Tax
noun.
/ owó sísan ìlú.
Tea
noun.
/ tii.
Teach
verb.
/ kọ lẹ́kọ, ọí níyè.
Teacher
noun.
/ olùkọ́.
Team
noun.
/ ẹgbẹ́, àkójọ ènìyàn láti se nkan.
Tear
noun.
/ ìfàya, omije, ẹkún.
verb.
/ fàyaya.
Tease
verb.
/ tọ, yọ́ lẹ́nu.
Teenager
noun.
/ ọ̀dọ́mọbìnrin tàbí ọ̀dọ́mọkùnrin.
Telephone
noun.
/ ẹrọ ìbàniṣọ̀rọ̀, tẹlifónù.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.