English - Yorùbá Dictionary

Sev

Seventh adj. /  èkeje.

Several adj. /  ọ̀pọ̀lọpọ̀, onírúrú.

Sex noun. /  ẹ̀ya obìnrin áti ọkùnrin.

Shade noun. /  ìbòji, òjìji.

Shadow noun. /  òjìji.

Shaft noun. /  ihò jínjìn, ọ̀pá.

Shake verb. /  mì, rù, gbọ̀n.

Shall verb. /  yio.

Shallow adj. /  sàìjinlẹ̀.

Shame noun. /  ìtìjú, àbùkù, ẹ̀gàn, ojútì, ẹ̀tẹ́.

Shameful adv. /  pẹ̀lú ìtìjú.

Shameless adj. /  láìnítìjú, gbójú.

Shape noun. /  ìrísí, àwóran, ìwo.

Share noun. /  ìpín. verb. / pín, se àjọpín.

Shareholder noun. /  alajọpín.

Sharp adj. /  mímú, yára se kan.

Sharpen verb. /  pọ́n, lọ̀, gbẹ ní sósóró.

She pron. /  ó, òn (obìnrin).

She

Shear verb. /  rẹ́, rẹ́ kúrú.

Shed noun. /  búkà, abúlé, abà.

Sheep noun. /  àgùtàn.

Shelter noun. /  àbò. verb. / dá bòbò.

Shift noun. /  ìsípò padà. verb. / yípadà.

Shin noun. /  ojúgun.

Shine verb. /  tàn, ran, dan, mọ́lẹ̀. noun. / ìmọ́lẹ̀.

Shiny adj. /  dídán.

Shock noun. /  ìgbọ̀n títí, ìjáyà.

Shoe noun. /  bàtà.

Shoelace noun. /  okùn bàtà.

Short adj. /  kúrú, kúkúrú.

Shortage noun. /  àìpé, dín.

Should verb. /  ìbá.

Shoulder noun. /  èjìká.

Shout noun. /  ariwo, hihó. verb. / pariwo, hó yè.

Shove verb. /  bì, tì síwájú. noun. / ìtìsíwájú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba