HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Sel
Seller
noun.
/ olùtà.
Selvage
noun.
/ etí aṣọ.
Seminar
noun.
/ ilé ẹ̀k ọ́ gíga.
Senate
noun.
/ àjọ ìgbìmọ̀.
Senetor
noun.
/ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ ilú.
Send
verb.
/ rán.
Senior
adj.
/ ẹ̀gbọ́n, àgbà, asájú.
Seniority
noun.
/ jíjùlọ ní ipò tàbí ní àgbà.
Sensation
noun.
/ ìmọ̀, àìbalẹ-ôkàn.
Sense
noun.
/ ìmọ̀, èrò, òye, ọgbọ́n.
Senseless
adj.
/ láìnímọ̀, láìní òye, láìlọ́gbọ́n.
Sensibility
noun.
/ tì tètè mọ̀.
Sensible
adj.
/ lóye, gbọ́n, ní ìmọ̀.
Sensitive
adj.
/ ìyára ní ìmọ̀, ní ìfura, tètè mọ̀ lára.
Sensitivity
noun.
/ yíyára ní ìmọ̀, níní ìfura, tì tètè mọ̀.
Sentence
noun.
/ ọ̀rọ̀ ìdájọ́, gbólóhùn ọ̀rọ̀.
verb.
/ dálẹ́bi.
Separate
verb.
/ ya nípa, yà sọ́tọ̀, pínyà.
Separation
noun.
/ ìyàsápákan, ìyàsọ́tọ̀, ìpínyà.
Sep
September
noun.
/ oṣù kẹsan ọdún.
Sequence
noun.
/ ìtọ̀lẹ́hìn.
Serf
noun.
/ ẹrú.
Serial
adj.
/ atẹ̀léra.
Series
noun.
/ ìtẹ̀lé lẹ́ṣẹṣẹ.
Serious
adj.
/ ní ìrònú, ṣe pàtàkì, léwu.
Sermon
noun.
/ ìwásù, ìkìlọ̀, ọ̀rọ̀ ìyànjú.
Serpent
noun.
/ ejò.
Servant
noun.
/ ìránsẹ́, ọmọ ọdọ̀.
Serve
verb.
/ ṣe ìránṣẹ́, sìn, se iṣẹ́ fún.
Service
noun.
/ ìsìn, iṣẹ́.
Session
noun.
/ ìjókó àwọn onídájọ́.
Set
noun.
/ àkójọpọ̀, ìpàtẹ eré.
Settle
verb.
/ túnṣe, san gbèsè, pinnu.
Settlement
noun.
/ ìtúnṣe, ìsanwó, ìlú títẹ̀dó.
Seven
noun.
/ méje, èje.
Seventeen
noun.
/ mẹ́tàdínlógún, ẹ̀tadínlógún.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.