English - Yorùbá Dictionary

Time

Time noun. /  ìgbà, àkókò, àsìkò.

Timeless adj. /  láinígbà, láiní àkókò.

Timid adj. /  níbẹ̀rù, lójo.

Tin noun. /  pángolo.

Tiny adj. /  kéré.

Tip noun. /  ẹbùn owó, ténté, ògógoro.

Tire noun. /  arẹ, lailagbara.

Tired adj. /  larẹ, rírẹ̀.

Title noun. /  oyé, orúkọ.

To prep. /  sí, sọ́dọ̀, láti.

Toad noun. /  ọ̀pọ̀lọ́.

Tobacco noun. /  ewé tábà.

Today adv. /  lóní, ọjọ́ òní.

Toe noun. /  ọmọ ìka ẹsẹ̀.

Together adv. /  jùmọ̀, lákòpọ, lẹ́gbẹ́, jọ, pẹ̀lú.

Toilet noun. /  ilé ìyàgbẹ́.

Told verb. /  wi, sọ, ro.

Tolerable adj. /  fífaradà, gbígbà.

Tol

Tolerance noun. /  ífaradà, gbígbà.

Tolerant adv. /  gbàfún.

Tolerate verb. /  gbà, faradà.

Toll noun. /  owó ibodè, ibodè, ìró agogo.

Tomorrow adv. /  ọla, lọla.

Tomtit noun. /  ẹyẹ ṣinṣin.

Ton noun. /  òsùwọ̀n.

Tongue noun. /  ahọ́n.

Tonight adv. /  lálẹ́ yí.

Too adv. /  pẹ̀lú, pọ̀jù.

Took verb. /  gba, mú, gbe.

Tool noun. /  ohun èlò.

Tooth noun. /  ehín.

Top noun. /  òkè, gongo òkè, ténté.

Topic noun. /  orí ọ̀rọ̀, kókó ọ̀rọ̀.

Torment noun. /  ìdálóró, ìyọlẹ́nu. verb. / dá lóró, yọ lẹ́nu.

Tornado noun. /  ẹfufu nlá, ìjì.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba