English - Yorùbá Dictionary

Tho

Thorn noun. /  ẹ̀gún.

Thorny adj. /  kìkí ẹ̀gún.

Thorough adj. /  jálẹ̀, jálẹ̀ ganran, pátápátá.

Thoroughly adj. /  ni pípépípé, pátápátá.

Those adj. /  àwọn.

Though conj. /  bí, bótilẹ̀jẹ́pé.

Thought adj. /  ìrò, ìsebi, àníyàn, èrò inú.

Thoughtful adj. /  lánìíyàn, lájò, ní èrò.

Thousand noun. /  ẹgbẹ̀rún.

Thread noun. /  okùn tínrín, òwú.

Threat noun. /  ìlọ̀, ìkìlọ̀, ìdẹ́rúbà, ìhalẹ̀mọ́.

Threaten verb. /  kìlọ, dẹ́rùbá, halẹ̀ mọ, pákuru mọ.

Three (3) noun. /  ẹta, mẹta.

Throat noun. /  ọfun, ọ̀nà ọfun.

Throb verb. /  lù, mí hẹlẹ, ṣọ kúlú.

Throne noun. /  ìtẹ́ ọba.

Throng noun. /  àwùjọ, àpéjọ, ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Throttle verb. /  fúnlọ́rùn, fúnlọ́fun.

Thr

Through adv. /  já, láti ìhà kan dé èkejì, nípa.

Throughout adv. /  jálẹ̀jálẹ̀, yíká, jákèjádò.

Throw noun. /  sísọ, jíjù, ìsọ̀kò. verb. / sọ, jù, fi sọ̀kò.

Thumb noun. /  àtànpàkò.

Thunder noun. /  àrá. verb. / san àrá.

Thursday noun. /  ọjọ́ karun ọṣẹ, àlàmísì, ọjọ́bọ̀.

Thus adv. /  báyí, bí irú èyí, báhun.

Thy pron. /  rẹ, tirẹ̀.

Thyself pron. /  iwọ tikalara.

Tick noun. /  àmi kékeré, égbọn.

Ticket noun. /  àmì ìwé ìgbàwọlé.

Tickle noun. /  rínrín. verb. / rín ní dùndún.

Tidy verb. /  se ìmọ́tótó. adj / nímọ̀tótó.

Tie noun. /  gbígba ipò kannà ní ìdíjé. verb. / dì, so, se kókó.

Tiger noun. /  àmọ̀tẹ́kùn.

Tight adj. /  há, fún, le, mọ, pinpin.

Tighten verb. /  fà le, mú le, so le.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba