English - Yorùbá Dictionary

Tra

Transfer verb. /  gbé láti ibì kan lọ sí ibi kejì.

Transferable adj. /  gbigbà lọ́wọ́ ẹni fi lé ẹnìkejì lọ́wọ́.

Transfiguration noun. /  ìpawọ́dà, ìparàdà.

Transfusion noun. /  fífún aláìsàn lẹ́jẹ̀, ìfúnni lẹ́jẹ̀.

Translate verb. /  túmọ̀.

Translation noun. /  ìtúmọ̀ èdè padà sí èdè míràn.

Translator noun. /  onìtumọ̀ èdè.

Transparent adj. /  ti a le wò láti fi ríran, ọkàn mímọ́.

Transport verb. /  kúrò láti ibìkan si ibìkan pẹ̀lú ọkọ̀.

Trap noun. /  okùn dídẹ, ìdẹkùn, tàkúté.

Trash noun. /  ohun lásán.

Travel noun. /  ìrìn àjò.

Traveller noun. /  alárìnkiri, arìnnà àjò.

Tray noun. /  ọpón.

Treason noun. /  ọ̀dàlẹ̀ ìlú.

Treasure noun. /  ọrọ̀, àlùmọ́nì.

Treasurer noun. /  ẹnití mójútó owó ẹgbẹ́.

Treasury verb. /  ìjọba ti mójútó owó ìlú.

Tre

Treat verb. /  tọ́jú, hùwà sí.

Treatment noun. /  ìlòsí ìwà, ìwòsàn.

Treaty noun. /  àdéhùn tàbí ìmùlẹ̀ lárin ìlú méjì.

Tree noun. /  igi.

Tremble verb. /  mì, gbọ̀n.

Trench noun. /  ihò tínrín tógùn.

Trespass noun. /  ìrékọjá.

Trespasser noun. /  olùrékọjá.

Trial noun. /  ìdánwò, ìpèlẹ́jọ́, ìwádí.

Triangle noun. /  onígun mẹ́ta.

Tribe noun. /  ẹ̀yà, irú ènìyàn.

Tribunal noun. /  ibi ìdájọ́.

Trick noun. /  ẹtàn, èrú, ìwàkíwà.

Trip noun. /  ìrìn àjò kúkúrú.

Troops noun. /  àwọn ọmọ ogun.

Trophy noun. /  ohun ìrántí, àmì ìsẹ́gun.

Trouble noun. /  ìpọ́njú, ìyọnu, ìjàngbọ̀n.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba