English - Yorùbá Dictionary

Tro

Trousers noun. /  sòkòtò gígùn, sòkòtò gbọrọ.

Truce noun. /  ìdáwọ́ ìjà dúró fún ìgbà kan.

True adj. /  nítòtọ́, lotọ.

Trunk noun. /  ara, ara ohunkóhun, ọwọ́ jà erin, ìtí igi.

Trust noun. /  ìgbẹ́kẹ̀lé, ìgbàgbọ́, ìfaratì.

Truth noun. /  òtítọ́, òdodo.

Truthful adj. /  kún fún òtítọ́.

Try noun. /  ìdánwò. verb. / dánwò.

Tub noun. /  ọpọ́n nlá.

Tube noun. /  ihò inú.

Tuesday noun. /  ọjọ́ kẹta ọsẹ, ọjọ́ ìsẹ́gun.

Tulip noun. /  orúkọ òdòdó kan.

Tumble noun. /  ìsubú, ìkọsẹ̀. verb. / subú, kọsẹ̀.

Tunnel noun. /  ihò ìsàlẹ̀ ilé tí ọkọ́ ngbà kọjà, ojú efín.

Turban noun. /  láwàní.

Turbulence noun. /  ìse rúdurùdu.

Turbulent adj. /  ní rúdurùdu, oníyọnu.

Turkey noun. /  tòlótòlò.

Turn

Turn noun. /  ìyípadà, ìyí. verb. / yípadà.

Tush inter. /  ṣiọ.

Tusk noun. /  eyín ọgan, eyín erin.

Tutor noun. /  olùkọ́.

Twelve (12) noun. /  méjìlá, èjìlá.

Twenty (20) noun. /  ogún.

Twice adv. /  lẹmejì, nígbà méjì, ẹmejì.

Twig noun. /  ọwọ́ igi, ẹ̀ka igi.

Twin noun. /  ìbejì, èjìrẹ́.

Twist verb. /  lọ́po.

Twitch verb. /  já pati, ja.

Two (2) noun. /  méjì, éjì.

Type noun. /  irú, àpẹrẹ, tẹ̀ ìwé.

Typewriter noun. /  ẹ̀rọ ìkọ̀wé.

Tyrannical adj. /  ika, rorò, níkà.

Tyrannize noun. /  se ika si, fi agbára lo nílòkulò.

Tyrant noun. /  ika ènìyàn, òṣìkà.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba