English - Yorùbá Dictionary

Une

Uneducated adj. /  láilẹkọ, tí kò kàwé.

Unemployed adj. /  ẹnití kòní iṣẹ́.

Unemployment noun. /  láláiníṣẹ́ lọ́wọ́.

Uneven adj. /  tí kò tẹju.

Unexpected adj. /  lójijì, láiretí.

Unfair adj. /  láitọ, tí kò lẹtọ.

Unfaithful adj. /  láiṣòtọ, láiṣòdodo.

Unfamiliar adj. /  láimọ, tí a kò mọ dáradára.

Unfinished adj. /  láisetán, láiparí.

Unfit adj. /  láiyẹ.

Unforgettable adj. /  láilègbàgbé.

Unforgivable adj. /  láilèdáríjì.

Unfortunate adj. /  láilóríire.

Unfortunately adv. /  óseni lánú, tí kò bọsi.

Unfriendly adj. /  láinífẹ ènìyàn.

Ungrateful adj. /  láimore.

Unhappy adj. /  láidunnú.

Unhealthy adj. /  láilágbára.

Uni

Uniform noun. /  asọ ẹgbẹ́.

Unify verb. /  ṣe sọkan, ṣe lọkan.

Unimportant adj. /  láise pàtàkì.

Union noun. /  ìdàpọ̀, ìsọ̀kan, ìrẹ́pọ̀.

Unique adj. /  láilẹ́gbẹ́.

Unit noun. /  ọ̀kan. verb. / ìdì kan.

Unite verb. /  sọ́ pọ̀, dàpọ̀, sọ̀kan, parapọ̀.

United adj. /  áso pọ̀, ìdàpọ̀.

Unity noun. /  sísopọ̀, dìdàpọ̀.

Unjust adj. /  láisotọ.

Unjustified adj. /  láinídí.

Unkind adj. /  láinínúre, ní ìkà.

Unknow adj. /  láimọ̀.

Unlawful adj. /  lòdì sófin.

Unless conj. /  àyàfi, àfi.

Unlikely adj. /  láijẹ́bẹ̀.

Unload verb. /  sọ ẹrù kalẹ̀, ja ẹrù ninu mọ́tọ̀.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba