HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Unl
Unlock
verb.
/ fi kọ́kọ́rọ́ sí.
Unloving
adj.
/ láini ìfẹ́.
Unlocky
adj.
/ láilóríre.
Unmanageable
adj.
/ tí apá ká ká.
Unmarked
adj.
/ láilámì, tí a kò sàmì sí.
Unmarried
adj.
/ láilọ́kọ tàbí ìyàwó.
Unmerciful
adj.
/ láilanu.
Unmixed
adj.
/ láidapọ.
Unmoveable
adj.
/ láiyẹsẹ̀.
Unnatural
adj.
/ láibá ìwà ẹ̀dá mu.
Unnecessary
adj.
/ láiyẹ.
Unnoticed
adj.
/ tí a kò se afiyesi.
Unnumbered
adj.
/ ainiye.
Unoccupied
adj.
/ láilò.
Unopposed
adj.
/ laidojuja kọ.
Unorganized
adj.
/ láito lẹṣẹṣẹ.
Unpack
verb.
/ lái di ẹrù, tú ẹrù.
Unpaid
adj.
/ láisan owó.
Unp
Unpardoned
adj.
/ láidáríjì.
Unpleasant
adj.
/ láiwù.
Unpopular
adj.
/ láilókìkí.
Unprepared
adj.
/ láimúra.
Unprofitable
adj.
/ láilérè.
Unprotected
adj.
/ láilabo.
Unproved
adj.
/ láiridi.
Unpunctual
adj.
/ láiwa ni àkókò.
Unqualified
adj.
/ láilóye, láiní ìmọ̀.
Unreal
adj.
/ tí kì íse òtítọ́, .
Unreliable
adj.
/ láilegbẹ́kẹ̀lé.
Unrenewed
adj.
/ láisọ di títun.
Unrest
noun.
/ àisimi.
Unrevealed
adj.
/ láìfihàn.
Unrevenged
adj.
/ laigbẹsan.
Unripe
adj.
/ laipọn.
Unsafe
adj.
/ léwu, ni jamba.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.