English - Yorùbá Dictionary

Var

Variable adj. /  yíyípadà.

Variation noun. /  íyípadà, ìyàtọ̀.

Variety noun. /  onírúrú, ìyàtọ̀, àmúlùmálà, ọ̀kankòjọ̀kan.

Various adj. /  onírúrú, ọ̀pọ̀lọpọ̀, láidájú.

Vary verb. /  yí padà, mú yàtọ̀, pàrọ̀.

Vase noun. /  ìgò tí a nfi òdòdó sí.

Vast noun. /  tótóbi, tí ó gbilẹ̀, nlá, gbòrò, pọ̀.

Vault noun. /  iyàrá abẹ́ ilẹ̀, ilé àfowópamọ́sí.

Veal noun. /  ẹran ọmọ málù.

Vegetable noun. /  ewéko, ewébẹ̀, ohun ọ̀gbin.

Vegetarian noun. /  ẹnití ti ki jẹ ẹran àfi ewébẹ̀.

Vegetate verb. /  hù, dàgbà, wà láyé bi ọ̀lẹ tàbí alaironu.

Vehicle noun. /  mọ́tò.

Veil noun. /  ìbojú.

Vein noun. /  isan ẹ̀jẹ̀.

Velocity noun. /  ìyára.

Velvet noun. /  asọ àrán.

Vend verb. /  ta ọjà.

Ven

Vendor noun. /  olùtajà, ọlọ́jà, atajà.

Vengeance noun. /  ẹ̀san, ìgbẹ̀san, ìjẹníyà.

Vent noun. /  ihò, ojú ẹ́na, afẹ́fẹ́, ọna ìsálọ.

Ventilate verb. /  jẹ kí afẹ́fẹ́ fẹ́ sí, kéde ní gbangba.

Ventilation noun. /  ìgba afẹ́fẹ́ rere, ìkéde ọrọ sí gbangba.

Ventilator noun. /  ẹnu ọna afẹ́fẹ́.

Veranda noun. /  fàrándà.

Verb noun. /  ọrọ ìse.

Verbal adj. /  fífẹnusọ, ti ọrọ sísọ, tí a fi ẹnu sọ.

Verdict noun. /  ìdájọ́, ìpinnu àwọn adájọ́.

Verification noun. /  ìfohùnsí, ìjẹ́rísí, òtítọ́.

Verify verb. /  fohùn sí, jẹrísí, òtítọ́.

Versatile adj. /  sípòpadà, yí padà, áidúró níbìkan.

Verse noun. /  ẹsẹ, ìwọn tí a pín orí ìwé sí.

Version noun. /  ìyípadà ni édè kan sí èkejì.

Versus prep. /  tàbí, dípò.

Vertex noun. /  ṣónṣó orí oke.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba