HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Vac
Vacancy
noun.
/ àyè, àfo.
Vacant
adj.
/ ṣófo.
Vacate
verb.
/ parẹ́, fi àyè sílẹ̀ fún, fi ipò sílẹ̀.
Vacation
noun.
/ ìsimi díẹ lẹ́yìn iṣẹ́, ọludé.
Vaccinate
verb.
/ gbà nanba, gbà abẹ́rẹ́ àjẹsára.
Vaccine
noun.
/ àjẹára.
Vacillate
verb.
/ mi siyin sohun, se iyemeji.
Vacuum
noun.
/ òfo, àlàfo, mọ́.
Vagabond
noun.
/ ipanle, isansa, alarinkiri.
Vagina
noun.
/ òbò.
Vagrant
adj.
/ rírìnkiri láiní ibùgbé.
Vague
adj.
/ àilẹ́sẹ̀nílẹ̀, àidúró níbìkan, ṣàidájú, ṣíkiri.
Vain
adj.
/ lófo, lásán, aláìnílárí, láinídì.
Vainglory
noun.
/ ògo asán.
Vale
noun.
/ àfonífojì òkè nlá.
Valediction
noun.
/ ìdágbére.
Valet
noun.
/ ọmọ ọ̀dọ̀ ọkùnrin tí ndúró ti ènìyàn.
Valiant
adj.
/ akọni, nígbòyà, lágbára.
Val
Valid
adj.
/ nipa, ti a fi ìdí rẹ̀ kalẹ̀ nínú òtítọ́ nípa òfin.
Validity
noun.
/ agbára, ipá, agbára òfin.
Valley
noun.
/ àfonífojì, àfo ilẹ̀ lárín òkè méjì.
Valorous
adj.
/ nígboyà, láibẹru, alágbára.
Valor
noun.
/ ìgboyà, ìwà akọni.
Valuable
adj.
/ níyelórí, lérèlórí, oníyebíye, lówólórí.
Valuation
noun.
/ ìdíyelé, ìfowólé.
Value
noun.
/ iye, iye owó, rírí, iyì.
Van
noun.
/ ọkọ̀ akérò.
Vandalism
noun.
/ ìbàjẹ́ ohun ìní láinídì.
Vanguard
noun.
/ ẹgbẹ́ ti o ṣaju ogun.
Vanish
verb.
/ yọ sálọ, fò lọ, fẹ́ lọ, di asán, di òfo.
Vanity
noun.
/ òfo, asán, ládòfo, ìgbéraga.
Vanquish
verb.
/ ṣẹ́gun, borí.
Vantage
noun.
/ ànfàní, àye, ère, ìrọ̀rùn.
Vapid
adj.
/ láiní ẹ̀mí, ṣíṣọ ẹ̀mí nù.
Vapor
noun.
/ oru.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.