English - Yorùbá Dictionary

Vit

Vituperate verb. /  bu, bá wí.

Vivacious adj. /  ni dárayá, ti o yára, ni gígùn ẹ̀mí.

Vivid adj. /  dárayá, dàbí ẹnipé o ní ẹ̀mí, hàn gbangba.

Vividly adv. /  sansan.

Vivify verb. /  sọ di àye.

Vixen noun. /  abo kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀, obìnrin onínú fùfù.

Vocable noun. /  ifọhun, ọ̀rọ̀, orúkọ.

Vocabulary noun. /  ìwé ìkójọ ọrọ ti a to lẹ́sẹ sẹ.

Vocal adj. /  ti o ni ohùn.

Vocalist noun. /  akọrin.

Vocation noun. /  ìpè, iṣẹ́.

Vociferate verb. /  ho, iho, sọ gburu.

Vociferation noun. /  igbe nlanla, asọ̀ gburu.

Vociferous adj. /  alásọ̀, onígbe.

Vodka noun. /  orúkọ ọtí mímu kan.

Voice noun. /  ohùn.

Voiceless noun. /  láiní ohùn.

Void adj. /  ṣófo, asán.

Vol

Volatile adj. /  yípadà lójìjì.

Volcano noun. /  òkè ti nma yọ efin ìgbàmíràn o le yọ iná.

Volley noun. /  ajọyin ibọn, ayinpọ ibọn.

Volleys verb. /  gbá tàbí jù bọlu ki ó tó kanlẹ̀.

Volt noun. /  agbára láti lo iná mọnanmọnan.

Volume noun. /  ọ̀pọ̀, ariwo. verb. / yín sókè.

Voluntary adj. /  àtinúwá, tinú tinú, tìfẹ́ tìfẹ́.

Volunteer noun. /  ẹnití ó nse iṣẹ́ láigbá owó.

Vomit verb. /  bì, pọ̀ jáde. noun. / ebi.

Voracious adj. /  niwọra nípa nkan.

Vote noun. /  ìbò, ìlohùnsí, yíyàn. verb. / dìbò, lohun si, yàn.

Voucher noun. /  sọ̀wé dowó.

Vow noun. /  ẹ̀jẹ́, ìlérí ìfẹ́. verb. / jẹ ẹ̀jẹ́, ṣe ìlérí.

Vowel noun. /  fáwẹ̀lì. ègé ọ̀rọ̀.

Voyage noun. /  ìrìn àjò ojú omi tàbí ofurufu.

Vulnerable adj. /  ẹnití kò sí agbára fún tí a lè palára.

Vulture noun. /  ẹyẹ ìgún, àkàlà, gúnugún,.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba