HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Wac
Wacky
adv.
/ aláwàdà, oníyẹ̀yẹ́.
Wad
noun.
/ idi ìwé, idi owó pépà.
Wade
verb.
/ fi ìṣoro rin kọjá, fi agbára rin kọjá.
Waffle
verb.
/ ṣọ tàbí kọ láiní ìtumọ̀ pàtàkì.
Waft
verb.
/ lọ sókè pẹ̀lú jẹ́jẹ́.
Wag
verb.
/ mìsọ́tùn mìsósì.
Wage
verb.
/ ṣe adehun, jiyàn, fi ìjiyàn lélẹ̀, gbógun.
Wages
noun.
/ owó iṣẹ́ lọ́ṣọ̀ṣẹ̀, owó.
Wagon
noun.
/ ọkọ̀ akẹ́rù.
Wail
verb.
/ sunkún sókè.
Waist
noun.
/ ìbàdí, ìdí.
Wait
verb.
/ dúró, dúró dè, dúró tì, retí.
Waiter
noun.
/ adúró tini, agbawó onjẹ.
Waiting room
noun.
/ ibi ìdúró dè sì.
Waive
verb.
/ ni àṣẹ láti se nkan.
Wake
verb.
/ jí, se àisùn, tají.
Walk
noun.
/ ìrìn.
verb.
/ rìn, fi ẹsẹ̀ rìn.
Wall
noun.
/ ògiri, ìgànná.
Wal
Wallet
noun.
/ àpamọ́ owó kékeré.
Walnut
noun.
/ àwùsá òyìnbó.
Wander
verb.
/ rìn kiri, sìnà kiri.
Wane
verb.
/ dínkù, yẹ diẹ diẹ, súnmọ́ òpin.
Want
noun.
/ fífẹ́, ìfẹ́.
verb.
/ fẹ́, se àiní.
War
noun.
/ ogun, ìjà.
verb.
/ jagun, bá jà, bá jagun.
Ward
noun.
/ yàrá nílé ìwósán.
Warden
noun.
/ olùṣọ́, olùtọ́jú, alábò.
Warder
noun.
/ ẹnití nsọ ẹlẹ́wọ̀n.
Wardrobe
noun.
/ ibi ipa aṣọ mọ́ si, aṣọ wíwọ̀.
Ware
noun.
/ ohun títà, ọjà.
Warehouse
noun.
/ ilè ìpamọ́ ọjà si.
Warm
adj.
/ gbóná diẹ, lílọ́ wọ́rọ́.
Warmth
noun.
/ ìgbóná, ìtara, ìfẹ́.
Warn
verb.
/ ṣe ìkìlọ̀ fún.
Warning
noun.
/ ìkìlọ̀.
Warp
noun.
/ títa okùn ìwunsọ.
verb.
/ yi sí apákan, tẹ.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.