HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
XYZ
Xenophobia
noun.
/ ẹru tàbí ìkórira àwọn ènìyàn láti ìlú òdìkejì.
Xerox
noun.
/ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé.
X-ray
noun.
/ ẹ̀rọ tón ya àwòrán inú ara.
Yacht
Yacht
noun.
/ ọkọ̀ ojú omi fún fàjì.
Yank
verb.
/ fà lẹkanna pẹ̀lú agbára.
Yard
noun.
/ àgbàlá, ọ̀pá ìwọn ẹlẹ́sẹ̀.
Yawn
noun.
/ yíyán.
verb.
/ yán.
Yeah
noun.
/ bẹni, bẹ na ni.
Year
noun.
/ ọdún, osù méjìlá.
Yearly
adv.
/ lọdọdun, ti ọdọdun kan.
Yearn
verb.
/ se iyọnu si.
Yeast
noun.
/ ìwúkàrà.
Yell
verb.
/ ké ramúramù, bú, kọ.
noun.
/ bíbú, kíkọ.
Yellow
adj.
/ pupa rúsúrúsú bí àwọ ìyeyè.
Yes
adv.
/ bẹ ni, òtọ, han.
Yesterday
adv.
/ àná, lánà.
Yet
Yet
adv.
/ síbẹ̀, síbẹ̀síbẹ̀, bí ó tilẹ̀ rí bẹ.
Yield
noun.
/ èrè, ẹsan iṣẹ́, ìkórè.
verb.
/ fi padà, san.
Yolk
noun.
/ pupa inú ẹyin.
You
pron.
/ ìwọ, ọ, ẹyín.
Young
noun.
/ èwe, ọ̀dọ́, nkan tí kò tí dàgbà púpọ̀.
Your
pron.
/ tìrẹ, tiyín.
Yourself
pron.
/ ìwọ tìkararẹ, ẹyin tìkara yín.
Youth
noun.
/ ọ̀dọ́mọdé, èwe.
Youthful
adj.
/ ti ọ̀dọ́mọdé, nígbà èwe.
Zealous
Zealous
adj.
/ níní tara nínú ohun gbogbo.
Zealously
adv.
/ pẹ̀lú ìtara.
Zebra
noun.
/ egbin.
Zenith
noun.
/ sonso, ìparí, ote, ibití ó ga jùlọ.
Zero (0)
noun.
/ òdo, òfo.
Zigzag
noun.
/ ségesège, wọrọwọrọ.
Zoo
noun.
/ ilé nlá ìpamọ́ àti ìfihàn onírúrú ẹranko.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.