English - Yorùbá Dictionary

Wor

Worker noun. /  òsìsẹ́.

World noun. /  ayé, aráyé.

World wide adj. /  gbogbo ayé, àgbáyé.

Worm noun. /  ejònu, aràn.

Worn adj. /  àlògbó, tí ó bàjẹ́.

Worried adj. /  kúnfún wàhálà, kúnfún ìjáyà.

Worry noun. /  wàhálà, ájò, ìnira.

Worse adj. /  burú jù.

Worship noun. /  ìsìn, iyìn, oyè. verb. / sin, foríbalẹ̀, jọ́sìn.

Worshipper adv. /  olùsìn.

Worst adj. /  burújùlọ, burú rékọjá.

Worth noun. /  iye, ìtọ́sí, jámọ́, iyì ìdíyelé.

Worthless adj. /  láitóye, láiníye lórí, láinílárí.

Worthy adj. /  nítóyè, tó, yẹ, lókìkí.

Would verb. /  yio, fẹ́.

Wound noun. /  ọgbẹ́, ìpalára, ìfarapa.

Wrangle noun. /  àròyé, ìjiyàn, asọ̀.

Wrap verb. /  dì, bò, fi wé, fi dì, ró.

Wra

Wrath noun. /  ìbínú.

Wreak verb. /  gbẹ̀san, fi ìbínú le.

Wreath noun. /  màrìwò, ìtanná ewéko.

Wreck noun. /  ìbàjẹ́ ọkọ̀.

Wrench noun. /  rírọ̀, ìré. verb. / fi agbára gbà, fà.

Wrestle verb. /  jìjàkadì, jagidigbo.

Wrestler noun. /  onijakadi.

Wriggle verb. /  kù siwa kù sẹ́hìn, yí ara kiri.

Wring verb. /  lọ́, fun, lọ́ mọ́ lọ́wọ́.

Wrinkle noun. /  ìwúnjọ, ìkíweje, ìkátì. verb. / fun pọ, wunjọ.

Wrist noun. /  ọrùn ọwọ́.

Writ noun. /  ìwé òfin.

Write verb. /  kọ, kọ̀wé, hàntú.

Writer noun. /  akọ̀wé.

Writing noun. /  ìkọ̀wé, ìwé.

Wrong adj. /  ìṣìnà, ìṣìṣe.

Wuss noun. /  ìbàjẹ́, bàwọ́n jẹ torí ẹru

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba