English - Yorùbá Dictionary

Bab

Babble verb. /  ṣọ wérewére, ṣòfófó,ṣọ àsírí.

Babbler noun. /  aláhesọ, olófofo, oníwikuwi.

Baby noun. /  ọmọ ọwọ́, ọmọ jòjòló.

Baboon noun. /  ọ̀bọ lágídò, ìnàkí.

Bachelor noun. /  àpọ́n.

Back adj. /  ẹ̀hìn. adv / lẹ́hìn.

Backbite verb. /  sọ̀rọ̀ ẹni lẹ́hìn.

Backbone noun. /  egungun ẹ̀hìn, ògóòró.

Background adj. /  ipó ẹ̀hìn, ìpìlẹ̀.

Backstay noun. /  fèhìntì, aláfẹ̀hìntì.

Backward adj. /  fàsehìn, padàsẹ́hìn.

Bacon noun. /  ẹran ẹlẹ́dẹ̀ sísè.

Bad adj. /  burú, burúkú, búburú.

Badge noun. /  àmì.

Baffle verb. /  dà-rú, s ọ-dasán.

Bag noun. /  àpò, ọkẹ́.

Bail noun. /  onígbọ̀wọ́, adúrófúnni, ìgbọ̀wọ́, ìdúró-fúnni.

Bailiff noun. /  ìjòyè, onídàájọ́, ọlọ́pàá.

Bake

Bake verb. /  sè, yan, dín.

Baker noun. /  adínkàrà, adín-nkan .

Bakery noun. /  ilé ibití àti dín nka.

Balance noun. /  ọgbọgba.

Balcony noun. /  àgbàlá, ọ̀dẹ̀dẹ̀, òde lókè ilé pẹtẹsì.

Bald adj. /  pípárí, àìnírunlórí.

Baldhead noun. /  apárí.

Baleful adj. /  kún fún ìkà, fún òsì.

Ballon noun. /  ọkọ́ ófúrufú.

Ballot noun. /  ìbò, ìwé ìdìbò.

Bamboo noun. /  ọparun, pàko.

Ban verb. /  dádúró, fi-bú.

Banana noun. /  ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹrẹ.

Band noun. /  èdìdì, ìgbánú, ẹgbẹ́ onílù, bẹmbẹ òyìnbó.

Bandage noun. /  ìrépé aṣọ ti afi ndi ọgbẹ́.

Bandit noun. /  olè, ọlọ́sà, aláìlófin.

Bane noun. /  ìparun, ikú.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba