HOME
ABOUT
PHONOLOGY
HISTORY
YORÙBÁ
English - Yorùbá Dictionary
Ban
Bang
noun.
/ lìlú.
Banish
verb.
/ lé lọ, lé kúrò ní ìlú, rán jáde.
Banishment
noun.
/ ilékúrò nílú.
Bank
noun.
/ bèbè, etí odò, ilé ifowó pamọ́.
Banker
noun.
/ ọ̀gá ilé ìfi owó pamọ́ sí .
Bankrupt
noun.
/ ajigbèsè, ẹnití owó bàjẹ́ mọ lọ́wọ́ .
Bankruptcy
noun.
/ ìbàjẹ́ owó.
Baptism
noun.
/ gbígba ènìyàn sínú ìjọ krístì.
Baptize
verb.
/ rì-sínú omi, rì bọ omi.
Bar
noun.
/ irin tàbi igi gbọrọ.
Barbarian
noun.
/ aláìgbédè, aláìmòye, ènìyànkénìyàn.
Barber
noun.
/ onígbàjámọ̀, fárífárí, agẹrun .
Bard
noun.
/ akéwì,akọrin, onírárà.
Bare
adj.
/ níhòhò, láìbò.
Barefoot
adj.
/ láìníbàtà, lẹ́sẹ̀ lásán, lẹ́sẹ̀ òfìfo.
Bargain
noun.
/ ìdùná-dùrà,ìpinnu, adehun.
Barge
noun.
/ ọkọ̀ ìgbájá.
Bark
noun.
/ gbígbó bí ajá,èpo igi.
verb
/ gbó bí ajá.
Barn
Barn
noun.
/ àká, abà.
Barometer
noun.
/ ohun èlo láti fi wọ̀n afẹ́fẹ́.
Barrack
noun.
/ ilé àwọn ọmọ-ogun.
Barrel
noun.
/ àgbá.
Barren
adj.
/ yàgàn, ṣá,láìléso.
Barricade
noun.
/ ìdínà,ìsagbáradì.
Barrier
noun.
/ ìdínà,agbára, àlà .
Barrister
noun.
/ agbẹjọ́rò, amòfin, lọ́yà .
Base
noun.
/ ìsàlẹ̀, ìpilẹ̀.
Baseborn
adj.
/ ọmọ àle.
Bashful
adj.
/ nítìjú, lójútì.
Basis
verb.
/ ìpilẹ̀.
Bask
verb.
/ yá orùn, yáná.
Basket
noun.
/ agbọ̀n, apẹ̀rẹ̀.
Bastard
noun.
/ ọmọ àle.
Bat
noun.
/ àdán .
Batch
noun.
/ àpopọ̀ nkan.
Back
Next
Donate
Your donation
, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email:
info@aroadedictionary.com
Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá
Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba
Your browser does not support the audio element.