English - Yorùbá Dictionary

Auc

Auction noun. /  gbànjo .

Auctioneer noun. /  onígbànjo.

Audacity noun. /  ìgbójú, àfojúdi, àyà níní.

Audience noun. /  àpèjọ ọ̀pọ̀ ènìyàn, olùwòran.

Audit noun. /  àyẹ̀wò ìwé owó.

Augury noun. /  àfọ̀ṣẹ .

August noun. /  oṣù kẹjọ ọdún.

Aunt noun. /  ègbọ́n lobìnrin.

Authentic adj. /  òdodo, tòótọ.

Author noun. /  ònkọwé , olùpilẹ̀.

Authority noun. /  agbára òfin, àṣẹ.

Authorize verb. /  fún láṣẹ, fún lágábra.

Autobiography noun. /  ìtàn ìgbésé ayé ẹni tí àkọsílè.

Automatic adj. /  sisẹ́ fún ararẹ̀.

Auxiliary noun. /  olùránlọ́wọ́.

Available adj. /  lérè ,ṣànfàní.

Avenge verb. /  gbẹ̀san, kọ̀ya.

Avenue noun. /  ojú ọ̀nà, àye.

Aversion

Aversion noun. /  ìrira, àiní ìfẹ́sí.

Avert verb. /  mú kúrò, dá dúró, yí padà.

Aviary noun. /  ilé ẹyẹ.

Avoid verb. /  yẹra fún, yàgò fún, bìlà fún.

Avouch verb. /  tẹnumọ́.

Avow verb. /  kéde nígbangba, jẹ́wọ́.

Await verb. /  retí, dúro dè, múra sílẹ̀ dè.

Awake adj. /  ìtají verb / jí lójú orun, tají.

Award noun. /  ẹ̀bùn. verb / pín fún, ṣe ìdájọ́ fún

Aware adj. /  fura, kíyèsí,mọ̀.

Away adv. /  kúrò, kálọ, jìnnà.

Awful adj. /  burújù, burú.

Awkward adj. /  wúru-wúru, àìrọrùn.

Awning noun. /  àtíbàbà.

Axe noun. /  àáké.

Axle noun. /  ọ̀pá onírin ti mú nkan rìn.

Aye adv. /  lailai.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba