English - Yorùbá Dictionary

Bath

Bath noun. /  ìwẹ, balùwẹ̀.

Battery noun. /  ohun ìja ogun,àgbá ogun.

Battle noun. /  ìjà, ogun.

Battlefield noun. /  ojú ogun.

Be verb. /  sí, ni, wà .

Beach noun. /  etí òkun, ẹ̀bá òkun.

Bead noun. /  ìlẹ̀kẹ̀.

Beak noun. /  ẹnu ẹyẹ, ìmú, agogo ẹyẹ .

Beam noun. /  ìtànsan òòrùn, ìtí igi.

Bean noun. /  eèré, ẹ̀wà, ẹwẹ.

Bearable adj. / ìfaradà, ìrọ́jú .

Beard noun. /  irùngbọ̀n .

Beat verb. /  lù, nà, fọ́, borí.

Beating noun. /  lílù, nínà.

Beautiful adj. /  dára,lẹ́wà, rẹwà.

Beauty noun. /  ẹwà, ọ̀ṣọ́, dídara.

Because conj. /  nítorí, nítorítí.

Become verb. /  bá, dé-sí, sọ-di.

Bed

Bed noun. /  ìbùsùn.

Bedroom noun. /  yàrá, iyàrá ìbùsùn, ìyẹ̀wù.

Bee noun. /  oyin, kòkòrò oyin.

Beef noun. /  ẹran-màlúù.

Beechive noun. /  ilé-oyin, afárá oyin.

Befit verb. /  yẹ, tọ́-sí.

Before prep. /  níwájú, síwájú .

Befriend verb. /  bá sọ̀rẹ́, bá rẹ́.

Beg verb. /  bẹ̀bẹ̀, tọrọ, ṣagbe.

Began verb. /  bẹ̀rẹ̀si, bẹ̀rẹ, ṣẹ̀.

Beggar noun. /  alágbe, atọrọjẹ, atúlẹjẹ, oní-bárà.

Beginner noun. /  ẹnití ó kọ́ bẹ̀rẹ nkan.

Beginning noun. /  àkóbẹ́rẹ́, ìbẹ̀rẹ̀ nkan , ìsẹ́dálè.

Behave verb. /  hùwà, lò.

Behead verb. /  bẹ́-lórí.

Behest noun. /  aṣẹ.

Behind prep. /  lẹ́hìn.

Back    Next

Donate


Your donation, helps the development
and keeps Dictionary alive.
by cheque: please email
Email: info@aroadedictionary.com

Òmìnira Ilẹ̀ Yorùbá


Orin-iyin ti orilẹ-ede Yoruba